Tue Jun 25 2019 12:03:42 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-25 12:03:43 +01:00
parent 0f0d55a592
commit e67fbf9412
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 19 Wón lu orì rẹ̀ pẹ̀lú ọ̀pá, wọ́n sì tu itọ́ síi lára. Wọ́n kúnlẹ̀ ní wájú rẹ̀ bíì pé wón júbà rè. \v 20 Nígbàtí wọ́n ti se ẹlẹ́yà rẹ̀, wọ́n bọ́ asọ ìgúnwà elése àlùkò náà, wọ́nsì fi asọ rẹ̀ wọ̀ọ́, wón sì mu lo lati kan mo agbelebu \v 21 Won fi ipa mu enikan ton koja lo leba ona lati gbe agbelebu Jesu, okunrin ti a npe oruke re ni Simoni ara Kireni, baba Alesanda ati Rufusi. \v 19 Wón lu orì rẹ̀ pẹ̀lú ọ̀pá, wọ́n sì tu itọ́ síi lára. Wọ́n kúnlẹ̀ ní wájú rẹ̀ bíì pé wón júbà rè. \v 20 Nígbàtí wọ́n ti se ẹlẹ́yà rẹ̀, wọ́n bọ́ asọ ìgúnwà elése àlùkò náà, wọ́nsì fi asọ rẹ̀ wọ̀ọ́, wón sì múu lọ láti kàán mọ́ àgbélèbú \v 21 Wọ́n fi ipá mú ẹnìkan tón kọjá lọ lẹ́bàá ọ̀nà láti gbé àgbelebu Jesu, okunrin ti a npe oruke re ni Simoni ara Kireni, baba Alesanda ati Rufusi.