Thu May 16 2019 15:29:18 GMT-0900 (Alaskan Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-16 15:29:19 -09:00
parent 83b12d61dd
commit e1d230acc4
2 changed files with 2 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 29 Jésù wípé, lóòtọ́ ni mo wí fún yin, kò sí ẹni tí ó fi ilé, tàbí arákùnrin tàbí arábìnrin tàbí ìyá tàbí bàbá tàbí àwọn ọmọ tàbí ilẹ̀ nítorí tèmi àti nítorí ìyìn-rere \v 30 tí kì yóò gbàá ní ìlọ́po ọgọ́rùnún ní ayé yìí: ilé àti, arákùnrin, àti arábìnrin, àti ìyá àti àwọn ọmọ àti ilẹ̀ pẹ̀lú inúnibíni àti ní ayé tí ńbọ̀ iyè aìnípẹ̀kun. \v 31 , Sùgbọ́n ọ̀pọ̀ àwọn ẹni iwájú ní yóò di ẹni ẹ̀yìn àti ẹni ẹ̀yìn yóò sì di ẹni iwájú."
\v 29 Jésù wípé, lóòtọ́ ni mo wí fún yin, kò sí ẹni tí ó fi ilé, tàbí arákùnrin tàbí arábìnrin tàbí ìyá tàbí bàbá tàbí àwọn ọmọ tàbí ilẹ̀ nítorí tèmi àti nítorí ìyìn-rere \v 30 tí kì yóò gbàá ní ìlọ́po ọgọ́rùnún ní ayé yìí: ilé àti, arákùnrin, àti arábìnrin, àti ìyá àti àwọn ọmọ àti ilẹ̀ pẹ̀lú inúnibíni àti ní ayé tí ńbọ̀ iyè aìnípẹ̀kun. \v 31 , ùgbọ́n ọ̀pọ̀ àwọn ẹni iwájú ní yóò di ẹni ẹ̀yìn àti ẹni ẹ̀yìn yóò sì di ẹni iwájú."

View File

@ -47,8 +47,8 @@
"10-20",
"10-23",
"10-26",
"10-29",
"10-32",
"10-35",
"10-38",
"10-41",
"10-43",