Wed Jun 26 2019 09:51:26 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-26 09:51:27 +01:00
parent ab8773f665
commit da5038c183
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 4 Pílátù tún bií, "Ìwo kò ní ìdáhùn ni? Wo iye ẹ̀sùn tí wọ́n fi sùn ọ́!" \v 5 Sùgbọ́n Jésù kò dá Pílátù lóhùn mọ́, èyí sì yàá ní ẹnu.
\v 4 Pílátù tún bií léèrè, "Ìwọ kò ní ìdáhùn ni? Wo iye àwọn ẹ̀sùn tí wọ́n fi kàn ọ́!" \v 5 Sùgbọ́n Jésù kò dá Pílátù lóhùn mọ́, èyí sì yàá ní ẹnu.