Tue Jun 25 2019 11:59:41 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-25 11:59:43 +01:00
parent df9d4e7766
commit d62217a6c7
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 19 Wón lu orì rẹ̀ pẹ̀lú ọ̀pá, wọ́n sì tu itọ́ síi lára. Wọ́n kúnlẹ̀ ní wájú rẹ̀ bíì pé wón júbà rè. \v 20 Nígbati won ti se eleya re, won bo aso igunwa elese aluko naa, wonsi fi aso re wo, won si muu lo lati kan mo agbelebu \v 21 Won fi ipa mu enikan ton koja lo leba ona lati gbe agbelebu Jesu, okunrin ti a npe oruke re ni Simoni ara Kireni, baba Alesanda ati Rufusi.
\v 19 Wón lu orì rẹ̀ pẹ̀lú ọ̀pá, wọ́n sì tu itọ́ síi lára. Wọ́n kúnlẹ̀ ní wájú rẹ̀ bíì pé wón júbà rè. \v 20 Nígbàtí wọ́n ti se ẹlẹ́yà rẹ̀, won bo aso igunwa elese aluko naa, wonsi fi aso re wo, won si muu lo lati kan mo agbelebu \v 21 Won fi ipa mu enikan ton koja lo leba ona lati gbe agbelebu Jesu, okunrin ti a npe oruke re ni Simoni ara Kireni, baba Alesanda ati Rufusi.