diff --git a/15/09.txt b/15/09.txt index 6240316..da539df 100644 --- a/15/09.txt +++ b/15/09.txt @@ -1 +1 @@ -\v 9 Pílátù dawọn lóhùn wípé, "Ǹjẹ́ ẹ̀yin fẹ́ kí èmi fi Ọba àwọn Júù lé e yín lọ́wọ́ ni?" \v 10 Nítorí ó mọ̀ pé àwọn olórí àlùfáà f i lé òun lọ́wọ́ nítorí owú \v 11 Sùgbọ́n àwọn olórí àlùfa ru àwọn èrò sókè láti pariwo pé Baraba ni kíó fi sílẹ̀. \ No newline at end of file +\v 9 Pílátù dawọn lóhùn wípé, "Ǹjẹ́ ẹ̀yin fẹ́ kí èmi fi Ọba àwọn Júù lé e yín lọ́wọ́ ni?" \v 10 Nítorí ó mọ̀ pé àwọn olórí àlùfáà fi Jésù lé òun lọ́wọ́ nítorí owú ni \v 11 Sùgbọ́n àwọn olórí àlùfa ru àwọn èrò sókè láti pariwo pé Baraba ni kí ó fi sílẹ̀. \ No newline at end of file