diff --git a/12/26.txt b/12/26.txt index 7c27832..46dab54 100644 --- a/12/26.txt +++ b/12/26.txt @@ -1 +1 @@ -\v 26 Ṣùgbọ́n nípa àjíǹde tó ti kú, ẹ̀yin kò ì tí ka nínú ìwé Mósè, àkọsílẹ̀ pápá tí ń jó, bí Ọlọ́run se bá Mósè sọ̀rọ̀ tó wípé, ‘Èmi ni Ọlọ́run Ábráhámù, Ọlọ́run Ísáákì àti Ọlọ́run Jákọ́bù’? \v 27 Òun kì í ṣe Ọlọ́run àwọn òkú, bí kò ṣe Ọlọ́run àwọn alààyè. nítorí ẹ̀yin ṣe àṣìṣe gidigidi.” \ No newline at end of file +\v 26 Ṣùgbọ́n nípa àjíǹde tó ti kú, ẹ̀yin kò ì tí ka nínú ìwé Mósè, àkọsílẹ̀ pápá tí ń jó, bí Ọlọ́run se bá Mósè sọ̀rọ̀ tó wípé, ‘Èmi ni Ọlọ́run Ábráhámù, Ọlọ́run Ísáákì àti Ọlọ́run Jákọ́bù’? \v 27 Òun kì í ṣe Ọlọ́run àwọn òkú, bí kò ṣe Ọlọ́run àwọn alààyè. Ẹ̀yin ṣe àṣìṣe gidigidi.” \ No newline at end of file diff --git a/12/28.txt b/12/28.txt new file mode 100644 index 0000000..cd1f79b --- /dev/null +++ b/12/28.txt @@ -0,0 +1,3 @@ +\v 28 Ọ̀kan nínú àwọn olùkọ́ òfin wá ó sì fetísílẹ̀ gbọ́ àròyé wọn; ó ṣàkíyèsí pé Jesu ti dáhùn dáradára. Òun pẹ̀lú sì béèrè lọ́wọ́ Jesu pé, “Nínú gbogbo òfin, èwo ló ṣe pàtàkì jùlọ?” +29 Jesu dá ọkùnrin yìí lóhùn pé, “Èyí tó ṣe pàtàkì jùlọ nínú àwọn òfin ni èyí tí ó kà báyìí pé: ‘Gbọ́ Israẹli; Olúwa Ọlọ́run wa Olúwa kan ni. 30Kí ìwọ kí ó fi gbogbo àyà rẹ, àti gbogbo ọkàn rẹ, àti gbogbo ẹ̀mí rẹ, àti gbogbo agbára rẹ fẹ́ Olúwa Ọlọ́run rẹ, èyí ní òfin kìn-ín-ní.’ 31Èkejì ni pé: ‘Fẹ́ ọmọnìkejì rẹ.’ Kò sí òfin mìíràn tó ga ju méjèèjì yìí lọ.” +\v 29 \v 30 \v 31 dd \ No newline at end of file diff --git a/manifest.json b/manifest.json index 17c8faf..0896172 100644 --- a/manifest.json +++ b/manifest.json @@ -100,6 +100,7 @@ "12-16", "12-18", "12-20", - "12-24" + "12-24", + "12-26" ] } \ No newline at end of file