Thu May 20 2021 14:46:13 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
aanuoluwapoadegoke 2021-05-20 14:46:13 +01:00
parent 8c541a65be
commit b332a721bc
3 changed files with 4 additions and 3 deletions

View File

@ -1,2 +1 @@
\v 16 Wọ́n mú owó idẹ kan fún Jésù. Ó wí fún wọn pé, “Àwòrán àti orúkọ ta ni èyí?” Wọ́n dáhùn pé, “Ti Kesari ni.” \v 17 Jesu wí fún wọn pé, “Bí ó bá rí bẹ́ẹ̀, ẹ fi ohun tí ó bá jẹ́ ti Kesari fún Kesari. Ṣùgbọ́n ẹ fi ohun gbogbo tí í ṣe ti Ọlọ́run fún Ọlọ́run.”
Ẹnu sì yà wọ́n gidigidi sí èsì rẹ̀.
\v 16 Wọ́n mú owó idẹ kan fún Jésù. Ó wí fún wọn pé, “Àwòrán àti orúkọ ta ni èyí?” Wọ́n dáhùn pé, “Ti Kesari ni.” \v 17 Jesu wí fún wọn pé, “Ẹ fi ohun tí ó bá jẹ́ ti Kesari fún Kesari, ohun tí í ṣe ti Ọlọ́run fún Ọlọ́run.” Ẹnu sì yà wọ́n gidigidi.

1
12/18.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 18 Àwọn Sadusi, tún wá sọ́dọ̀ rẹ̀, tí kò gbàgbọ́ pé àjíǹde ń bẹ. Ìbéèrè wọn ni pé, 19“Olùkọ́, Mose fún wa ní òfin pé: Nígbà tí ọkùnrin kan bá kú láìbí ọmọ, arákùnrin rẹ̀ gbọdọ̀ ṣú ìyàwó náà lópó kí wọn sì bímọ ní orúkọ ọkọ tí ó kú náà. \v 19 ss

View File

@ -96,6 +96,7 @@
"12-06",
"12-08",
"12-10",
"12-13"
"12-13",
"12-16"
]
}