diff --git a/12/32.txt b/12/32.txt index 398f1e8..e03bb62 100644 --- a/12/32.txt +++ b/12/32.txt @@ -1,2 +1 @@ -\v 32 Olùkọ́ òfin náà dáhùn pé, “Olùkọ́, ìwọ sọ òtítọ́ pé Ọlọ́run kan ni ó wà, àti pé kò sí òmíràn lẹ́yìn rẹ̀. -\v 33 Àti kí a fi gbogbo ọkàn, àti gbogbo òye, àti agbára fẹ́ ẹ, àti fẹ́ ọmọnìkejì ẹni bí ara ẹni, ó ju gbogbo ẹbọ sísun, àti ẹbọ lọ.” \v 34 Nígbà tí Jesu rí i dájú pé ó ti dáhùn pẹ̀lú òye, Ó wí fún un pé, “Ìwọ kò jìnà sí ìjọba Ọlọ́run.” Láti ìgbà náà lọ, ẹnikẹ́ni kò tún béèrè ohun kan lọ́wọ́ Jesu. \ No newline at end of file +\v 32 Olùkọ́ òfin náà dáhùn pé, “Olùkọ́, ìwọ sọ òtítọ́ pé Ọlọ́run kan ni ó wà, àti pé kò sí òmíràn lẹ́yìn rẹ̀. \v 33 Àti kí a fi gbogbo ọkàn, àti gbogbo òye, àti agbára fẹ́ ẹ, àti fẹ́ ọmọnìkejì ẹni bí ara ẹni, ó ju gbogbo ẹbọ sísun, àti ẹbọ lọ.” \v 34 Nígbà tí Jesu rí i dájú pé ó ti dáhùn pẹ̀lú òye, Ó wí fún un pé, “Ìwọ kò jìnà sí ìjọba Ọlọ́run.” Láti ìgbà náà lọ, ẹnikẹ́ni kò tún béèrè ohun kan lọ́wọ́ Jesu. \ No newline at end of file diff --git a/manifest.json b/manifest.json index 465cb59..20955dd 100644 --- a/manifest.json +++ b/manifest.json @@ -105,7 +105,6 @@ "12-28", "12-32", "12-35", - "12-38", "12-41", "12-43" ]