Fri Jul 09 2021 08:57:35 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2021-07-09 08:57:35 +01:00
commit a0e9e53ef2
73 changed files with 149 additions and 2 deletions

1
01/01.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\c 1 \v 1 Èyí ni Ìbẹ̀rẹ̀ ìhìnrere ti Jésù Kristì, Ọmọ Ọlọ́run. \v 2 Gẹ́gẹ́ bí a ti kọ ọ́ nínú ìwé wòlíì Isaiah pé: “Wò ó, Èmi ń ran oníṣẹ́ mi síwájú rẹ, Ẹni tí yóò tún ọ̀nà rẹ ṣe.” \v 3 “Ohùn ẹni tí ń kígbe ní ijù, ‘Ẹ tún ọ̀nà Olúwa ṣe, ẹ ṣe ojú ọ̀nà rẹ̀ kí ó tọ́.

1
01/04.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 4 Johanu dé, ẹni tí ó ń tẹnibọmi ní aginjù, tí ó sì ń wàásù ìtẹ̀bọmi ìrònúpìwàdà fún ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀. \v 5 Gbogbo ilẹ̀ Judea àti gbogbo ènìyàn Jerusalẹmu jáde tọ̀ ọ́ lọ, a sì ti ọwọ́ rẹ̀ tẹ gbogbo wọn bọ omi ni odò Jordani, wọ́n sì ń jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ wọn. \v 6 Johanu sì wọ aṣọ irun ìbákasẹ ó sì di àmùrè awọ mọ́ ẹ̀gbẹ́ rẹ̀, ó sì ń jẹ eṣú àti oyin ìgàn.

1
01/07.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 7 Ó wàásù wí pé, “Ẹnìkan ń bò tí ó lágbára jù mí lọ, èmi kò tọ́ ní ẹni tí ń wólẹ̀ láti tú okùn bàtà rẹ̀. \v 8 Èmi ń fi omi ṣe ìtẹ̀bọmi yín, ṣùgbọ́n Òun yóò fi Ẹ̀mí Mímọ́ ṣe ìtẹ̀bọmi yín.”

1
01/09.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 9 Ó sì ṣe ní ọjọ́ wọn nì tí Jesu ti Nasareti ti Galili wá, a sì ti ọwọ́ Johanu ṣe ìtẹ̀bọmi fún ní odò Jordani. \v 10 Bí Jésù se ti inú omi jáde wá, ó rí ọ̀run tí ó ṣí sílẹ̀, Ẹ̀mí Mímọ́ bí àdàbà sọ̀kalẹ̀ lé e lórí. \v 11 Ohùn kan sì ti ọ̀run wá wí pé, “Ìwọ ni àyànfẹ́ Ọmọ mi. Inú mi dùn sí o gidigidi.”

1
01/12.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 12 Ẹ̀mí Mímọ́ náà sì darí Rẹ̀ sí inù aginjù. \v 13 Ó sì wà ní aginjù fún ogójì ọjọ́, ti Satani ń dán an wò. Ó sì wà pẹ̀lú àwọn ẹranko ìgbẹ́, àwọn angẹli sì ń ṣe ìránṣẹ́ fún un.

1
01/14.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 14 Nísinsìyí lẹ́yìn ìgbà tí a mú Johanu sínú ẹ̀wọ̀n, Jesu wá sí Galili, ó ń wàásù ìhìnrere ti Ọlọ́run. \v 15 Ó ń wí pé, “Àkókò náà dé wàyí, ìjọba Ọlọ́run kù sí dẹ̀dẹ̀. Ẹ yípadà kí ẹ sì gba ìhìnrere yìí gbọ́.”

1
01/16.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 16 Nígbà ti ó ń rìn létí Òkun Galili, Ó rí Simoni àti Áńdérù arákùnrin rẹ̀, wọ́n ń fi awọ̀n wọn pẹja, torí pé apẹja ni wọ́n. \v 17 Jesu sì wí fún wọn pé, “Ẹ wa, ẹ tẹ̀lé mi, Èmi yóò sì sọ yín di apẹja ènìyàn.” \v 18 Ní kánkán wọ́n fi àwọ̀n wọn sílẹ̀, wọ́n sì tẹ̀lé e.

1
01/19.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 19 Bí Jésù sì ti rìn síwájú díẹ̀, Ó rí Jakọbu ọmọ Sébédè àti Jòhánù arákùnrin rẹ̀, wọ́n wa nínú ọkọ̀ wọ́n ń tún àwọ̀n wọn ṣe. \v 20 Ó ké wọn, wọ́n sì fi Sébédè baba wọn sílẹ̀ nínú ọkọ̀ pẹ̀lú àwọn alágbàṣe, wọ́n sì tọ̀ ọ́ lẹ́yìn.

1
01/21.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 21 Lẹ́yìn náà wọ́n wọ Kápérnáúmù, nígbà tí ó di ọjọ́ ìsinmi, Jésù lọ sínú Sínágọ́gù ó sì ń kọ́ni. \v 22 Ẹnu sì yà wọ́n nítorí ìkọ́ni rẹ̀, nítorí pé ó ń kọ́ni bí ẹni tí ó ní àṣẹ, kì í ṣe bí àwọn olùkọ́ òfin.

1
01/23.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 23 Nígbànáà ọkùnrin kan tí ó wà nínú Sínágọ́gù wọn, tí ó ní ẹ̀mí àìmọ́ bẹ̀rẹ̀ sí í kígbe, \v 24 wí pé, “Kí ni àwa ní se pèlu rẹ, Jésù ti Násárẹ́tì? Ṣé ìwọ wá láti pa wá run ni? Èmí mọ ẹni tí ìwọ í ṣe; Ìwọ ní ẹni Mímọ́ Ọlọ́run!” \v 25 Jesu si bá èmí èsù náà wí, ó wí pé, “Pa ẹnu rẹ mọ́, kí ó sì jáde kúrò lára rẹ̀!.” \v 26 Ẹ̀mí àìmọ́ náà sì gbé e sánlè, ó sì jáde kúrò lára ọkùnrin náà bí ó ti ń ké ní ohùn rara.

1
01/27.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 27 Ẹnu sì ya àwọn ènìyàn, tó bẹ́ẹ̀ tí wọ́n fi ń bi ara wọn pé, "Irú kíni èyí? Ẹ̀kọ́ tuntun pẹ̀lú àsẹ? Ó tún pàṣẹ fún àwọn ẹ̀mí àìmọ́ wọ́n sì gbọ́ tirẹ̀!” \v 28 Ìròyìn nípa rẹ̀ tàn ká gbogbo agbègbè Galili.

1
01/29.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 29 Nígbà tí wọn sì jáde kúrò nínú Sínágọ́gù, wọ́n lọ sí inú ilé Símónì àti Áńdérù pẹ̀lú Jákọ́bù àti Jòhánù . \v 30 Ìyá- ìyàwó Simoni tí ó dùbúlẹ̀ àìsàn ibà, wọ́n sì sọ fún Jésù nípa rẹ̀. \v 31 Ó sì wá, ó fà á lọ́wọ́, ó sì gbé e dìde; ibà náà si fi sílẹ̀, ó sì ń ṣe ìránṣẹ́ fún wọn.

1
01/32.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 32 Ní àṣálẹ́, tí oòrùn ti wọ̀, wọ́n gbé gbogbo àwọn aláìsàn àti àwọn tó ni ẹ̀mí àìmọ́ tọ̀ ọ́ wá. \v 33 Gbogbo ìlú si péjọ ni ẹnu-ọ̀nà. \v 34 Ó sì wo ọ̀pọ̀ tí ó ní onírúurú ààrùn sàn, ó sì tún lé ọ̀pọ̀ ẹ̀mí àìmọ́ jáde, ṣùgbọ́n kò jẹ́ kí àwọn ẹ̀mí àìmọ́ náà sọ̀rọ̀ nítorí tí wọ́n mọ̀ ọ́.

1
01/35.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 35 Ó sì dìde ní kùtùkùtù òwúrọ̀, kí ilẹ̀ tó mọ́, Ó kúrò ó sì lọ sí ibi tí ó dákẹ̀ láti lọ gbàdúrà. \v 36 Símónì àti àwọn tí ó wà pẹ́lu rẹ̀ lọ láti wá a. \v 37 Wọ́n rí I wọ́n sì wí fún pé, “Gbogbo ènìyàn ń wá ọ!”

1
01/38.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 38 Ó wí pé, “Ẹ jẹ́ kí a lọ sí àwọn ibò mìíràn, sí àwọn ìlú tí ó wà ní agbègbè, kí ń lè wàásù níbẹ̀ pẹ̀lú. Nítorí èyí ni mo ṣe wá.” \v 39 Ó ń lọ káàkiri gbogbo agbègbè Galili, ó ń wàásù nínú Sinagọgu Ó sì ń lé àwọn ẹ̀mí àìmọ́ jáde.

1
01/40.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 40 Ọkùnrin adẹ́tẹ̀ kan tọ̀ ọ́ wá. Ó sì ń bẹ̀ẹ́; ó kúnlẹ̀ níwájú rẹ̀ ó wí fún n pé, “Bí ìwọ bá fẹ́, ìwọ lè sọ mí di mímọ́.” \v 41 Àánú sì se é, Jésù na ọwọ́ rẹ̀ ó sì fi ọwọ́ rẹ̀ bà a, ó wí pé, “Èmí fẹ́. Di mímọ́.” \v 42 Lójúkan náà ẹ̀tẹ̀ náà fi sílẹ̀ lọ, ó sì di mímọ́.

1
01/43.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 43 Jésù sì kìlọ̀ fún un gidigidi ó sì rán an lọ. \v 44 Ó wí fún n pé, “Rí i dájú pé o kò sọ ohunkóhun fún ẹnikẹ́ni, ṣùgbọ́n lọ fi ara rẹ̀ hàn àlùfáà, kí o sì mú ẹ̀bùn lọ́ fún ìwẹ̀nùmọ́ rẹ èyí tí Mósè pàṣẹ, èyí tí í ṣe ẹ̀rí fún wọn.”

1
01/45.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 45 Ṣùgbọ́n ó jáde lọ, ó bẹ̀rẹ̀ sí í pòkìkí, ó ń tan ìròyìn kálẹ̀ tóbẹ́ẹ̀ gẹ́ tí Jésù kò sì le wọ ìlú kankan mọ́. Ó sì dúró ní ibi ìdákẹ́jẹ́, àwọn ènìyàn tọ̀ ọ́ wá láti ibi gbogbo.

1
01/title.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
Orí Kínní

1
04/01.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\c 4 \v 1 Ó tún bẹ̀rẹ̀ sí ń kọ́ni létí òkun, ọpọ̀ ènìyàn si yíi ká. Ó bọ́ sínú ọkọ̀ ojú omi tí ó wà lórí òkun, àwọn ènìyàn sì wà ní étí òkun. \v 2 Ó kọ́ wọn ní ohun púpọ̀ pẹ̀lú òwe, ẹ̀yí ni ojun tí ó wí fún wọn.

1
04/03.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 3 “Ẹ fi etí sílẹ̀, afúnrúgbìn náà jáde lọ láti lọ fúnrúgbìn rẹ̀. \v 4 Bí ó ti ń fúnrúgbìn, díẹ̀ bọ́ sí ẹ̀bá ọ̀nà, àwọn ẹyẹ sì wá, wọ́n sì ṣà á jẹ. \v 5 Díẹ̀ bọ́ sórí ilẹ̀ àpáta, níbi tí erùpẹ̀ ko sí púpọ̀. Lójúkannáà ó hu jáde, nítorí wọn kò ní erùpẹ̀ púpọ̀.

1
04/06.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 6 Ṣùgbọ́n nígbà tí oòrùn mú gangan, ó jóná, nítorí tí kò ní gbòǹgbò, ó gbẹ. \v 7 Àwọn irúgbìn mìíràn sì bọ́ sáàrín ẹ̀gún, nígbà tí ẹ̀gún sì dàgbàsókè, ó fún wọn pa, tó bẹ́ẹ̀ tí àwọn irúgbìn náà kò so èso.

1
04/08.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 8 Òmíràn bọ́ sí ilẹ̀ ọlọ́ràá, o sì so èso bí ó se ń dágbà tí ó sì ń gbilẹ̀, òmíràn so lọ́gbọọgbọ̀n, òmíràn lọ́gọọgọ́ta, àti òmíràn lọ́gọọgọ́rùn-ún.” \v 9 Ó sì wí pé, “Ẹni tí ó bá ní etí láti fi gbọ́, kí ó gbọ́!”

1
04/10.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 10 Nígbà tí ó ku Jésù nìkan, àwọn tì ó sú mọ́ ọ àti ọmọ-ẹ̀yìn méjìlá bi í léèrè ìtumọ̀ òwe. \v 11 Ó sì dá wọn lóhùn pé, “Ẹ̀yin ni a fi adìtú ìjọba Ọlọ́run. Ṣùgbọ́n gbọgbọ rẹ̀ jẹ́ ówẹ́ fún àwọn tí ó wà ní ta, \v 12 wìpé bí wọ́n bá wò, bẹ́ẹ̀ni wọ́n wò, ṣùgbọ́n wọn kò ríran, Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wí pé wọ́n gbọ́, bẹ́ẹ̀ni wọn gbọ́, kì yóò yé wọn, dípò bẹ́ẹ̀ ni wọn yóò sì yípadà, Ọlọ́run yíò sì dárí ẹ̀ṣẹ̀ jì wọ́n!’ ”

1
04/13.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 13 Ó sì wí fún wọn pé, “Sé òwe yìí kò yé e yín ni? Báwo ni ẹ̀yin yóò ṣe mọ ìtumọ̀ àwọn òwẹ mìíràn? \v 14 Afúnrúgbìn tí ó ǹ fúnrúgbìn ni ó ń fúnrúgbìn ọ̀rọ̀ náà. \v 15 Èyí ǐ ni àwọn tó bọ́ sí ojú ọ̀nà, níbi tí a fúnrúgbìn ọ̀rọ̀ sí, ṣùgbọ́n nígbà tí wọ́n gbọ́ ọ̀rọ̀ náà, lójúkan náà èṣù wá ó sì mú ohun tí wọ́n ti gbìn kúrò.

1
04/16.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 16 Èyí ni àwọn tí ó bọ́ sórí àpáta, nígbà tí wọ́n bá gbọ́ ọrọ̀ náà, lójúkanánáà wọ́n fi ayọ̀ gbà á. \v 17 Ṣùgbọ́n wọn kò ni gbòǹgbò nínú u wọn, Ṣùgbọ́n wọ́n faradàá fún ìgbà díẹ̀. Lẹ́yìn náà ni wàhálà tàbí inúnibíni dìde nítorí ọ̀rọ̀ náà, lójúkan náà, wọ́n subú.

1
04/18.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 18 Àwọn tí ó kù ni àwọn tí ó bọ́ sáàrín ẹ̀gún. Wọn gbọ́ ọ̀rọ̀ náà, \v 19 Ṣùgbọ́n àwọn afẹ́ ayé, ẹtàn ti ọrọ̀ àti àti afẹ́ àwọn ohun mèremère ayé, gba ọkàn wọn, wọ́n sì fún ọ̀rọ̀ náà pa, kò sì so èso. \v 20 Ṣùgbọ́n àwọn tí ó bọ́ sí ilẹ̀ ọlọ́ràá, ní àwọn tí ó gbọ́ ọ̀rọ̀ tí wọ́n sì gbà á, wọ́n sì mú èso púpọ̀ jáde- ní ọgbọọgbọ̀n, ọgọọgọ́ta, àti òmíràn ọgọọgọ́rùn-ún, gẹ́gẹ́ bí a ti gbìn ín.”

1
04/21.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 21 Jésù wí fún wọn pé, “A ha lè gbé fìtílà wọ inú ilé láti fi sábẹ́ agbọ̀n tàbí sábẹ́ àkéte? a o gbé e ka orí ọ̀pá fìtílà ni. \v 22 Nítorí kò sí ohun tí ó pamọ́ tí a kò ní fihàn, bẹ́ẹ̀ ni kò sí ohun tí ó wà ní ìkọ̀kọ̀, tí kò ní wá sí gbangba. \v 23 Bí ẹnikẹ́ni bá ní etí láti fi gbọ́, kí ó gbọ́!”

1
04/24.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 24 Ó wí fún wọn pé, “Ẹ máa kíyèsi ohun tí ẹ bà gbọ́, nítorí òṣùwọ̀n tí ẹ̀yin bá fi wọ́n náà ni a ó fi wọ́n fún un yín, a ó sì tún fi kún n fún n yín. \v 25 Nítorí ẹni tí ó bá ní, òun ni a ó tún fi fún sí i, àti lọ́wọ́ ẹni tí kò bá ní, ni a ó ti gba èyí náà tí ó ní.”

1
04/26.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 26 Ó sì tún sọ pé, “Ìjọba Ọlọ́run dàbí okùnrin kan tí ó ń fúnrúgbìn sí ilẹ̀. \v 27 Ó ń sùn ní óru àti ní ọ̀sán ó dìde, irúgbìn náà hu jáde, ó sì dàgbà, òun kò sì mọ̀ bí ó ti ṣẹlẹ̀. \v 28 Nítorí tí ilẹ̀ hù èso jáde fún ara rẹ̀: ó mú èéhù ewé jáde, lẹ́yìn náà ní orí ọkà, ní ìparí ní orí ọkà tí ó ti gbó. \v 29 Nígbà tí èso bá gbó tán, lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, òun a tẹ dòjé bọ inú ọkà náà, nítorí ìkórè ti dé."

1
04/30.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 30 Ó sì tún wí pé, “Kí ni a ò bá fi ìjọba Ọlọ́run wé, tàbí òwe wo ni a lè fi ṣe àkàwé rẹ̀? \v 31 Ó dàbí èso hóró musitadi, nígbàt ó jọ ọ̀kan nínú àwọn èso tí ó kéré jùlọ ti a gbìn sínú ilẹ̀. \v 32 Síbẹ̀, nígbà tí a gbìn ín, ó dàgbàsókè, ó gbilẹ̀, ó sì di títóbi ju gbogbo ewéko inú ọgbà yòókù lọ, ó sì yọ ẹ̀ka ńlá, tóbẹ̀ tí àwọn ẹyẹ ọ̀run lè kọ́ ìtẹ́ wọn sí ìbòji rẹ̀.

1
04/33.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 33 Òun lo ọ̀pọ̀ irú òwe wọ̀nyí láti ba àwọn ènìyàn sọrọ̀, gẹ́gẹ́ bí wọ́n bá ti ní òye tó, \v 34 kò sì bá wọn sọ̀rọ̀ láì lo òwe. Ṣùgbọ́n nígbà tí ó dá wà, ó sàlàyé gbọgbọ rẹ̀ fún àwọn ọmọ ẹyìn rẹ̀.

1
04/35.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 35 Ní ọjọ́ náà, nígbà tí alẹ́ lẹ́, ó wí fún wọn pé, “Ẹ jẹ́ kí a rékọjá sí apá kejì.” \v 36 Wọ́n fi ọpọ̀ erò sílẹ̀, wọ́n mú Jésù pẹ̀lú wọn, gẹ́gé bí ó ti wà nínú ọkọ̀ ojú omi. Àwọn ọkọ̀ ojú omi míiràn ń bá a lọ. \v 37 Ìjì líle ńlá kan sì dìde, omi sì ń bù sínú ọkọ̀, tó bẹ́ẹ̀ tí ọkọ̀ fi bẹ̀rẹ̀ sí í kún fún omi.

1
04/38.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 38 Jesu ti sùn lọ lẹ́yìn ọkọ̀, ó gbé orí lé ìrọ̀rí. Wọ́n sì jí i wọ́n wí pé, “Olùkọ́ni, ǹjẹ́ ìwọ kò tilẹ̀ bìkítà pé gbogbo wa fẹ́ kú?” \v 39 Ó dìde, ó bá ìjì líle náà wí, ó sì wí fún òkun pé, “Àlááfíà! Dákẹ́ Jẹ́ẹ́!” Ìjì náà sì dá, ìparọ́rọ́ ńlá sì wà.

1
04/40.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 40 Lẹ́yìn náà ó wí fún wọn pé, “Èéṣe tí ẹ̀yin fi ń bẹrù? Tàbí ẹ̀yin kò ì tí ì ní ìgbàgbọ́ síbẹ̀síbẹ̀?” \v 41 Ẹ̀rù bà wọ́n gidigidi, wọ́n sì wí fún ara wọn pé, “Irú ọkùnrin wo ni èyí, tí ìjì àti Òkun ń gbọ́ tirẹ̀?”

1
04/title.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
Orí Kẹẹ̀rin

1
08/01.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\c 8 \v 1 Ní ọjọ́ wọǹnì, bí ọ̀pọ̀ ènìyàn ti péjọ, wọn kò sí ní oúnjẹ láti jẹ. Jesu pe àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀, ó wí fún wọn pé, \v 2 “Àánú ọ̀pọ̀ ènìyàn wọ̀nyí ṣe mí, nítorí pé ó tó ọjọ́ mẹ́ta tí wọ́n ti wà pẹ̀lú ù mi kò sì sí ohun tí wọn yóò jẹ. \v 3 Bí mo bá rán wọn lọ sí ilé wọn láì jẹun, wọn le dákú lójú ọ̀nà. Àwọn mìíràn nínú wọn ti ọ̀nà jíjìn wá.” \v 4 Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ dá a lóhùn pé, “Níbo ni a ó ti rí àkàrà tí ó tó láti fi bọ́ wọn nínú aṣálẹ̀ yìí?”

1
08/05.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 5 Jesu béèrè lọ́wọ́ wọn pé, “Ìṣù àkàrà mélòó lẹ ní lọ́wọ́?” Wọ́n wípé, “Méje.” \v 6 Ó pàṣẹ fún ọ̀pọ ènìyàn náà láti jókòó lórí ilẹ̀. Ó mú àkàrà méje náà, ó dúpẹ́, ó sì bù wọ́n sí wẹ́wẹ́. Ó fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ láti gbé sí iwájú àwọn ènìyàn, wọ́n sì ṣe bẹ́ẹ̀.

1
08/07.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 7 Wọ́n tún ní àwọn ẹja wẹ́wẹ́ díẹ̀ pẹ̀lú, lẹ́yìn tí ó dúpẹ́, ó pàṣẹ fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ láti pín wọn fún àwọn ènìyàn náà. \v 8 Wọ́n jẹun wọ́n sì yó, wọ́n kó àjẹkù ti ó kù jọ, agbọ̀n méje sì kún. \v 9 Àwọn tí ó wà níbẹ̀ tó ìwọ̀n ẹgbàajì ènìyàn. Ó sì rán wọn lọ. \v 10 Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, ó wọ inú ọkọ̀ ojú omi pẹ̀lú àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀, wọ́n sì lọ sí agbègbè Dálímánútà.

1
08/11.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 11 NÍgbànáà ni àwọn Farisí jáde wá, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí ń se àríyànjiyàn pẹ̀lú u rẹ̀. Wọ́n ń wá ààmì láti ọ̀run wá lọ́wọ̀ ọ rẹ̀, láti dán an wò. \v 12 Ó mí kanlẹ̀ ní ọkàn an rẹ̀ ó wípé, “Èéṣe tí ìran yìí fi ń wá ààmì? Lóòótọ́ ni mo wí fún un yín, kò si ààmì tí a ó fi fún ìran yín.” \v 13 Nígbà náà ni fi wọ́n sílẹ̀, ó padà sínú ọkọ̀ ojú omi, ó sì rékọjá sí apá kejì Òkun náà.

1
08/14.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 14 Àwọn ọmọ ẹ̀yìn ti gbàgbé láti mú àkàrà lọ́wọ́. Ẹyọ ìṣù àkàrà kan ṣoṣo ni ó wà nínú ọkọ̀ wọn. \v 15 Jesu kìlọ̀ fún wọn pé, “Ẹ máa ṣọ́ra nítorí ìwúkàrà àwọn Farisí àti ìwúkàrà Hẹ́rọ́dù.”

1
08/16.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 16 Àwọn ọmọ ẹyìn sí bẹ̀rẹ̀ sí ronú èyí láàrín ara wọn wí pé, “Torí pé a kò mú àkàrà lọ́wọ́ ni” \v 17 Jesu mọ ohun tí wọ́n sọ láàrín ara wọn, ó sì dá wọn lóhùn pé, “Èéṣe ti ẹ̀yin fi ń ṣe àròyé pé ẹ̀yin kò mú àkàrà lọ́wọ́? Sé ẹ̀yin kò kíyèsi ni? Sé kò tilẹ̀ yẹ yín ni? Tàbí ọkàn ti rẹ̀wẹ̀sì?

1
08/18.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 18 Ẹ̀yin ní ojú, sé ẹ kò ríran ni? Ẹ̀ ni etí, sé ẹ kò sí gbọ́ran? Ǹjẹ́ ẹ̀yin kò rántí? \v 19 Nígbà ti mo bu ìṣù àkàrà márùn-ún fún ẹgbẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n ènìyàn, agbọ̀n mélòó ni ó kún fún àjẹkù tí ẹ ṣàjọ?” Wọ́n wí fún n pé, “Méjìlá.”

2
08/20.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1,2 @@
\v 20 “ Nígbà tí mo bọ́ ẹgbàajì pẹ̀lú ìṣù àkàrà méje, agbọ̀n mélòó ni ẹ kó jọ?” Wọ́n dáhùn pé, “Méje.”
\v 21 Ó sì wí fún wọn pé, “Sé kò tilẹ̀ tíì yé yin ni?”

1
08/22.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 22 Nígbà tí wọ́n dé Bẹtisaídà. Àwọn ènìyàn tí ó wà níbẹ̀ mú afọ́jú kan wá, wọ́n sì bẹ Jésù kí ó fi ọwọ́ kàn án. \v 23 Jesu fa ọkùnrin náà lọ́wọ́, ó sì mú un jáde lọ sí ẹ̀yìn ìlú. Nígbà tí ó tu itọ́ sí i lójú, Ó gbé ọwọ́ rẹ̀ lé e, Ó sì bi í léèrè pé, “Ǹjẹ́ ìwọ rí ohunkóhun?”

1
08/24.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 24 Ó wo okè, ó wípé, “Mo rí àwọn ènìyàn ti wọ́n n rìn kiri bí igi.” \v 25 Nígbànáà, Jesu tún gbé ọwọ́ rẹ̀ lé ojú rẹ̀, ọkùnrin náà sì la ojú u rẹ̀, a dá ìran rẹ̀ padà, ó sì rí gbogbo nǹkan kedere. \v 26 Jesu sì rán an sí ilé e rẹ̀, Ó wí fún n pé, “Má ṣe lọ sí ìlú. "

1
08/27.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 27 Jesu àti àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ jáde lọ sí àwọn abúlé ní agbègbè Kesaréà Fílípì. Lójú ọnà, ó bi àwọn ọmọ ẹyìn rẹ̀ pé, “Ta ni àwọn ènìyàn ń fi mí pè?” \v 28 Wọ́n dáhùn pé, “Jòhánù Onítẹ̀bọmi. Àwọn mìíràn wí pé, "Èlíjàh", àwọn míràn si wípé ọ̀kan nínú àwọn wòlíì."'

2
08/29.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1,2 @@
\v 29 Ó sì bi wọ́n pé, “Ṣùgbọ́n ta ni ẹ̀yin ń fi mí pè?”
Peteru dáhùn pé, “Ìwọ ni Kristi náà.” \v 30 Jesu kìlọ̀ fún wọn, kí wọn má sọ fún ẹnikẹ́ni nípa òun.

1
08/31.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 31 Ó sì bẹ̀rẹ̀ sí kọ́ wọn pé, Ọmọ Ènìyàn kò le ṣàìmá jìyà ohun púpọ̀, a ó sì kọ̀ ọ́ sílẹ̀ láti ọwọ́ àwọn àgbàgbà, àwọn olórí àlùfáà àti àwọn olùkọ́ òfin, a ó sì pa á, lẹ́yìn ọjọ́ mẹ́ta yóò sì jíǹde. \v 32 Ó sọ èyí láìfi ohunkóhun pamọ́ fún wọn. Pétérù pe Jésù sẹ́yìn, ó sì bẹ̀rẹ̀ si bá a wí.

1
08/33.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 33 Ṣùgbọ́n Jesu yípadà, ó wo àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀. Ó sì dá Pétérù lẹ́kun, “Kúrò lẹ́yìn mi, Sàtánì! Ìwọ kò ro ohun tí Ọlọ́run bí kò ṣe ohun tí ènìyàn.” \v 34 Nígbànáà ni Jesu pe àwọn ọ̀pọ̀ ènìyàn àti àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ jọ, ó wí fún wọn pé, “Bí ẹnikẹ́ni bá fẹ́ tọ̀ mí lẹ́yìn, ó gbọ́dọ̀ sẹ́ ara rẹ̀, kí ó gbé àgbélébùú rẹ̀, kí ó si máa tọ̀ mi lẹ́yìn.

1
08/35.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 35 Nítorí ẹni tó bá gbìyànjú láti gba ẹ̀mí ara rẹ̀ là, yóò sọ ọ́ nù, ẹni tí ó bá sì sọ ẹ̀mí rẹ̀ nù nítorí í tèmi àti nítorí ìhìnrere, òun náà ni yóò gbà á là. \v 36 Nítorí èrè kí ni ó jẹ́ fún ẹni tí ó jèrè gbogbo ayé, tí ó sọ ẹ̀mí rẹ̀ nù? \v 37 Kí ni ènìyàn yóò fi ṣe pàṣípàrọ̀ ẹ̀mí rẹ̀?

1
08/38.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 38 Ẹnikẹ́ni tó bá tijú àti gbà mí tàbí ọ̀rọ̀ mi nínú ìran panṣágà àti ẹlẹ́ṣẹ̀ yìí, Ọmọ Ènìyàn yóò tijú rẹ̀ nígbà tí ó bá padà dé nínú ògo Baba rẹ̀, pẹ̀lú àwọn angẹli mímọ́.”

1
08/title.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
Orí Kẹẹ̀jọ

1
12/01.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\c 12 \v 1 Nígbànáà ni Jésù bẹ̀rẹ̀ sí í fi òwe kọ́ wọn. Ó wípe, “Ọkùnrin kan gbin ọgbà àjàrà kan, Ó ṣe ọgbà yìí ká, ó sì wá ilẹ̀ fún ìfúntí wáìnì. Ó kọ́ ilé ìṣọ́, ó sì fi ṣe àgbàtọ́jú fún àwọn olùṣọ́gbà. Ó sì lọ sí ìrìnàjò. \v 2 Lákokò tí ó tọ́, ọkùnrin náà rán ọ̀kan nínú àwọn ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ̀ sí àwọn olùṣọ́gbà náà, kí ó gbà nínú èso ọgbà àjàrà náà lọ́wọ́ àwọn olùṣọ́gbà. \v 3 Ṣùgbọ́n wọ́n mú u, wọ̀n lù ú, wọ́n sì rán an padà lọ́wọ́ òfo.

1
12/04.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 4 Ó sì tún rán ọmọ ọ̀dọ̀ mìíràn sí wọn, ṣùgbọ́n wọ́n dá ọgbẹ́ sí i lórí, wọn rán an lọ ni ìtìjú. \v 5 Ó sì tún rán òmíràn, èyí nì wọ́n sì pa. wọ́n lu òmíràn wọ́n sì pa òmíràn.

1
12/06.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 6 “Ó ní ẹnìkan síi láti rán, èyí ni àyànfẹ́ ọmọ rẹ̀. Níkẹyìn ó ran an sí àwọn olùṣọ́gbà náà. Ó wípé, Wọn yóò bu ọlá fún ọmọ mi. \v 7 “Ṣùgbọ́n àwọn olùṣọ́gbà wí fún ara wọn pé, Èyí yìí ni àrólé. Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí a pa á, ogún rẹ̀ yóò sì jẹ́ tiwa.

1
12/08.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 8 Wọ́n mú ọmọ, wọ́n sì pa á, wọ́n sì wọ́ òkú rẹ̀ jáde kúrò nínú ọgbà àjàrà náà. \v 9 Ńjẹ́ kí ni olúwa ọgbà àjàrà yóò ṣe? Òun yíò wá láti pa àwọn olùsọ́gbà ni run, òun yóò sì fún àwọn mìíràn ní ọgbà rẹ̀.

1
12/10.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 10 Tàbí ẹ̀yin kò ì tí ka ẹsẹ yìí nínú ìwé mímọ́? Òkúta tí àwọn ọ̀mọ̀lé kọ̀sílẹ̀, òun náà ni ó di pàtàkì igun ilé. \v 11 Èyí wá láti ọdọ̀ Olúwa, ó sì jẹ́ ìyàlẹ́nu lójú tiwa?” \v 12 Wọ́n ń wá ọnà láti mú Jesu, ṣùgbọ́n ẹ̀rù ń bà wọ́n nítorí ọ̀pọ̀ ènìyàn tó wà lọ́dọ̀ rẹ̀, nítorí tí wọ́n mọ̀ pé àwọn ló ń pòwe mọ́. Nítorí náà wọ́n fi í sílẹ̀ lọ.

1
12/13.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 13 NÍgbànáà ni wọ́n rán àwọn Farisí pẹ̀lú àwọn kan tí í ṣe ọmọ-ẹ̀yìn Herodu wá sọ́dọ̀ Jesu, láti fi ọ̀rọ̀ rẹ̀ mú. \v 14 Bí wọn ti dé, wọ́n wí pé: “Olùkọ́, àwa mọ̀ pé ìwọ máa ń sọ òtítọ́ láìsí ìbẹ̀rù ẹnikẹ́ni. Òtítọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ni ìwọ máa ń kọ́ni. Ńjẹ́ ó tọ́ tàbí kò tọ́ láti máa san owó orí fún Kesari?” Kí àwa kí ó san án, tàbí kí a máa san án? \v 15 Ṣùgbọ́n Jesu mọ ìwà àgàbàgebè wọn, Ó sì wí pé, “Èéṣe tí ẹ̀yin fi n dán mi wo? Ẹ mú owó idẹ kan wá kí n wò ó.”

1
12/16.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 16 Wọ́n mú owó idẹ kan fún Jésù. Ó wí fún wọn pé, “Àwòrán àti orúkọ ta ni èyí?” Wọ́n dáhùn pé, “Ti Kesari ni.” \v 17 Jesu wí fún wọn pé, “Ẹ fi ohun tí ó bá jẹ́ ti Kesari fún Kesari, ohun tí í ṣe ti Ọlọ́run fún Ọlọ́run.” Ẹnu sì yà wọ́n gidigidi.

1
12/18.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 18 Nígbànáà ni àwọn Sadusí, tí ó wípé kò sí àjíǹde, tún wá sọ́dọ̀ rẹ̀. Wọ́n biì léèrè pé, \v 19 “Olùkọ́, Mose fún wa ní òfin pé, 'Nígbà tí ọkùnrin kan bá kú láìbí ọmọ, arákùnrin rẹ̀ gbọdọ̀ ṣú ìyàwó náà lópó kí wọn sì bímọ ní orúkọ ọkọ tí ó kú náà.

1
12/20.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 20 Àwọn arákùnrin méje kan wà; èyí tí ó dàgbà jùlọ gbéyàwó, ó sì kú ní àìlọ́mọ. \v 21 Arákùnrin rẹ̀ kejì ṣú obìnrin tí ó fi sílẹ̀ lópó, òun pẹ̀lú tún kú láìbímọ. Bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ni arákùnrin kẹta. \v 22 Àwọn méjèèje kò sì fi ọmọ sílẹ̀, Ní ìkẹyìn gbogbo wọn, obìnrin náà kú pẹ̀lú. \v 23 Ǹjẹ́ ní àjíǹde, nígbà tí wọ́n bá jíǹde, aya ta ni yóò ha ṣe nínú wọn? Àwọn méjèèje ni ó sá ni ní aya?”

1
12/24.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 24 Jesu wí fún wọn pé, “Kì í há ṣe nítorí èyí ni ẹ ṣe ṣìnà, nítorí ẹ̀yin kò mọ ìwé Mímọ́ tàbí agbára Ọlọ́run? \v 25 Nítorí pé, nígbà tí wọ́n bá jí dìde nínú òkú, a kò ní ṣe ìgbéyàwó fún wọn, ṣùgbọ́n wọn dàbí àwọn angẹli tí ń bẹ ní ọ̀run.

1
12/26.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 26 Ṣùgbọ́n nípa àjíǹde tó ti kú, ẹ̀yin kò ì tí ka nínú ìwé Mósè, àkọsílẹ̀ pápá tí ń jó, bí Ọlọ́run se bá Mósè sọ̀rọ̀ tó wípé, Èmi ni Ọlọ́run Ábráhámù, Ọlọ́run Ísáákì àti Ọlọ́run Jákọ́bù? \v 27 Òun kì í ṣe Ọlọ́run àwọn òkú, bí kò ṣe Ọlọ́run àwọn alààyè. Ẹ̀yin ṣe àṣìṣe gidigidi.”

1
12/28.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 28 Ọ̀kan nínú àwọn olùkọ́ òfin wá ó sì fetísílẹ̀ gbọ́ àròyé wọn; ó ṣàkíyèsí pé Jesu ti dáhùn dáradára. Òun pẹ̀lú sì béèrè lọ́wọ́ Jesu pé, “Nínú gbogbo òfin, èwo ló ṣe pàtàkì jùlọ?” \v 29 Jesu dáhùn ó wípé, “Èyí tó ṣe pàtàkì jùlọ ni, Gbọ́ Ísráẹ́lì; Olúwa Ọlọ́run wa, Olúwa kan ni. \v 30 Kí ìwọ kí ó fi gbogbo àyà rẹ, àti gbogbo ọkàn rẹ, àti gbogbo ẹ̀mí rẹ, àti gbogbo agbára rẹ fẹ́ Olúwa Ọlọ́run rẹ.' \v 31 Èkejì ni pé: Fẹ́ ọmọnìkejì rẹ gẹ́gẹ́ bíi ara à rẹ. Kò sí òfin mìíràn tó ga ju èyí lọ.”

1
12/32.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 32 Olùkọ́ òfin náà dáhùn pé, “Olùkọ́, ìwọ sọ òtítọ́ pé Ọlọ́run kan ni ó wà, àti pé kò sí òmíràn lẹ́yìn rẹ̀. \v 33 Àti kí a fi gbogbo ọkàn, àti gbogbo òye, àti agbára fẹ́ ẹ, àti fẹ́ ọmọnìkejì ẹni bí ara ẹni, ó ju gbogbo ẹbọ sísun, àti ẹbọ lọ.” \v 34 Nígbà tí Jesu rí i dájú pé ó ti dáhùn pẹ̀lú òye, Ó wí fún un pé, “Ìwọ kò jìnà sí ìjọba Ọlọ́run.” Láti ìgbà náà lọ, ẹnikẹ́ni kò tún béèrè ohun kan lọ́wọ́ Jesu.

1
12/35.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 35 Jesu dáhùn nígbà tí ó ń kọ́ ni nínú tẹ́ḿpílì, ó wípé, “Èéṣe tí àwọn olùkọ́ òfin fi wí pé Kristi ní ọmọ Dáfídì? \v 36 Dáfídì tìkára rẹ̀, nípa Ẹ̀mí Mímọ́ sọ̀rọ̀ wí pé, “Olúwa sọ fún Olúwa mi pé,“Jókòó ní ọwọ́ ọ̀tún mi, títí èmi yóò fi sọ àwọn ọ̀tá rẹ di àpótí ìtìsẹ̀ rẹ.' \v 37 Dáfídì tìkára rẹ̀ pè é ní Olúwa, Báwo ni Olúwa tún ṣe lè jẹ́ ọmọ Dáfídì?” Ọ̀pọ̀ ènìyàn sì fi ayọ̀ gbọ́ ọ̀rọ̀ rẹ̀.

1
12/38.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 38 Nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ Jésù wípé, “Ẹ ṣọ́ra fun àwọn olùkọ́ òfin, tí wọ́n fẹ́ láti máa wọ aṣọ gígùn káàkiri, tí wọ́n sì fẹ́ ìkíni ní ọjà \v 39 àti ibùjókòó ọlá nínú Sínágọ́gù àti ipò ọlá níbi àsè. \v 40 Wọ́n a tún máa jẹ ilé àwọn opó rún, tí wọ́n sì ń gbàdúrà gígùn fún àsehàn. Àwọn wọ̀nyí yíò wa ìdálẹ́bi púpọ̀."

1
12/41.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 41 Jésù sî jókòó ní òdìkejì kọjú sí àpótí ìṣúra ní tẹ́ḿpílì; ó ń wo ìjọ ènìyàn ti ń sọ owó sínú àpótí ìṣúra. Opọ̀ àwọn ọlọ́rọ̀ sì sọ púpọ̀ sí i. \v 42 Ṣùgbọ́n obìnrin opó kan wà, ó sì fi ààbọ̀ owó idẹ méjì síbẹ̀, tí ì ṣe ìdá méjì owó-babà kan sínú rẹ̀.

1
12/43.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 43 Ó pe àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀, ó sọ fún wọn wí pé, “Lóòótọ́ ni mo wí fún yin pé, tálákà opó yìí fi sínú àpótí ìṣúra ju gbogbo àwọn ìyókù to sọ sínú rẹ lọ. \v 44 Nítorí pé, àwọn ìyókù mú nínú ọ̀pọ̀ ìní wọ́n wá. Sùgbọ́n ní ti opó yǐ, nínú àìní rẹ̀, ó fi gbogbo ohun tí ó ní sílẹ̀.

1
12/title.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
Orí Kejìlá

1
front/title.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
Máákù

View File

@ -46,7 +46,8 @@
"OYEKOLA VICTOR OYEYEMI",
"Faith Opade",
"EDUNOLAOLUWA",
"olayemioladeji"
"olayemioladeji",
"aanuoluwapoadegoke"
],
"finished_chunks": [
"10-title",
@ -230,6 +231,78 @@
"06-48",
"06-51",
"06-53",
"06-56"
"06-56",
"front-title",
"01-title",
"01-01",
"01-04",
"01-07",
"01-09",
"01-12",
"01-14",
"01-16",
"01-19",
"01-21",
"01-23",
"01-27",
"01-29",
"01-32",
"01-35",
"01-38",
"01-40",
"01-43",
"01-45",
"04-title",
"04-01",
"04-03",
"04-06",
"04-08",
"04-10",
"04-13",
"04-16",
"04-18",
"04-21",
"04-24",
"04-26",
"04-30",
"04-33",
"04-35",
"04-38",
"04-40",
"08-title",
"08-01",
"08-05",
"08-07",
"08-11",
"08-14",
"08-16",
"08-18",
"08-20",
"08-22",
"08-24",
"08-27",
"08-29",
"08-31",
"08-33",
"08-35",
"08-38",
"12-title",
"12-01",
"12-04",
"12-06",
"12-08",
"12-10",
"12-13",
"12-16",
"12-18",
"12-20",
"12-24",
"12-26",
"12-28",
"12-32",
"12-35",
"12-38",
"12-41",
"12-43"
]
}