Thu May 16 2019 15:15:18 GMT-0900 (Alaskan Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-16 15:15:19 -09:00
parent 1ec4a1f425
commit 9ec5393996
3 changed files with 3 additions and 3 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\c 10 \v 1 Jésù fi ibẹ̀ sílẹ̀ ó lọ sí agbègbè Jùdéà àti sí ìkọjá odò Jọ́rdánì, ọ̀pọ̀ àwọn èrò sì tún tọ̀ọ́ wá. ó tún nkọ́ wọn lẹ́ẹ̀kan si gẹ́gẹ́bí ó ti má n se. \v 2 Nígbànáà ni àwọn Farisí wá sọ́dọ̀ọ rẹ̀ láti dán-an wò wọ́n bèrè wípé, " ǹjẹ́ ó bá òfin mu kí ọkọ kó ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀?" \v 3 ó dá wọn lóhùn, " kínni Mósè palásẹ fún yín?" \v 4 Wọ́n wípé, "Mósè fi àyè gba ọkùnrin láti kọ ìwé ìkọ̀sílẹ̀ kí ó sì lée jáde."
\c 10 \v 1 Jésù fi ibẹ̀ sílẹ̀ ó lọ sí agbègbè Jùdéà àti sí ìkọjá odò Jọ́rdánì, ọ̀pọ̀ àwọn èrò sì tún tọ̀ọ́ wá. ó tún nkọ́ wọn lẹ́ẹ̀kan si gẹ́gẹ́bí ó ti má n se. \v 2 Nígbànáà ni àwọn Farisí wá sọ́dọ̀ọ rẹ̀ láti dán-an wò wọ́n bèrè wípé, " ǹjẹ́ ó bá òfin mu kí ọkọ k ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀?" \v 3 ó dá wọn lóhùn, " kínni Mósè palásẹ fún yín?" \v 4 Wọ́n wípé, "Mósè fi àyè gba ọkùnrin láti kọ ìwé ìkọ̀sílẹ̀ kí ó sì lée jáde."

View File

@ -1 +1 @@
\v 5 "Nítorí ọkàn líle yín ni ó se kọ òfin wọ̀nyí fún yín," Jésù wí fún wọn bẹ́ẹ̀. \v 6 Sùgbọ́n láti ìpilẹ̀ṣẹ̀ ìṣẹ̀dá, 'ọlọ́run dá wọn ní akọ àti abo'.
\v 5 "Nítorí ọkàn líle yín ni ó se kọ òfin wọ̀nyí fún yín," Jésù wí fún wọn bẹ́ẹ̀. \v 6 ùgbọ́n láti ìpilẹ̀ṣẹ̀ ìṣẹ̀dá, 'ọlọ́run dá wọn ní akọ àti abo'.

View File

@ -37,7 +37,7 @@
],
"finished_chunks": [
"10-title",
"10-05",
"10-01",
"10-07",
"10-10",
"10-13",