Wed Jun 26 2019 10:47:26 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-26 10:47:27 +01:00
parent 50f352fe9f
commit 99d75a41b2
3 changed files with 3 additions and 3 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 19 Wón lu orì rẹ̀ pẹ̀lú ọ̀pá wọ́n sì tu itọ́ síi lára. Wọ́n kúnlẹ̀ ní wájú rẹ̀ bíì pé wón júbà rè. \v 20 Nígbàtí wọ́n ti fi se ẹlẹ́yà tán, wọ́n bọ́ asọ ìgúnwà elése àlùkò náà wọ́n sì fi asọ rẹ̀ wọ̀ọ́, wón sì múu lọ láti kàán mọ́ àgbélèbú \v 21 Wọ́n fi ipá mú ẹnìkan tó n kọjá lọ lẹ́bàá ọ̀nà láti gbé àgbélèbú Jésù, ọkùnrin tí à n pé orúkọ rẹ̀ ní Símónì ará Kírénì, bàbá Alesanda àti Rufusi.
\v 19 Wón lu orì rẹ̀ pẹ̀lú ọ̀pá wọ́n sì tu itọ́ síi lára. Wọ́n kúnlẹ̀ ní wájú rẹ̀ bíì pé wón júbà rè. \v 20 Nígbàtí wọ́n ti fi se ẹlẹ́yà tán, wọ́n bọ́ asọ ìgúnwà elése àlùkò náà wọ́n sì fi asọ rẹ̀ wọ̀ọ́, wón sì múu lọ láti kàán mọ́ àgbélèbú \v 21 Wọ́n fi ipá mú ẹnìkan tó n kọjá lọ lẹ́bàá ọ̀nà láti gbé àgbélèbú Jésù, ọkùnrin tí à n pé orúkọ rẹ̀ ní Símónì ará Kírénì, bàbá Alesándérù àti Rúfọ́sì.

View File

@ -1 +1 @@
\v 22 Àwọn ọmọ ọgun náà mú Jésù lọ ibi tí à npè ní Golgota (èyí tí ìtumọ̀ rẹ̀ njé, "Ibi agbárí"). \v 23 Wọ́n fun ní wáínì tí a pò pẹ̀lú òjía, sùgbọ́n kò muú \v 24 Wón kàán mọ́ àgbélèbú, wọ́n sì sẹ́ gègé láti pín asọ rẹ̀ láàrin ara wọn.
\v 22 Àwọn ọmọ ọgun náà mú Jésù lọ ibi tí à ńpè ní Golgota (èyí tí ìtumọ̀ rẹ̀ njé, "Ibi agbárí"). \v 23 Wọ́n fun ní wáínì tí a pò pẹ̀lú òjía, sùgbọ́n kò muú \v 24 Wón kàán mọ́ àgbélèbú, wọ́n sì sẹ́ gègé láti pín asọ rẹ̀ láàrin ara wọn.

View File

@ -43,7 +43,7 @@
"15-12",
"15-14",
"15-16",
"15-22",
"15-19",
"15-25",
"15-29",
"15-31",