From 99a6ddbca81643d8cc1c14d3203a4ff6406f7cb6 Mon Sep 17 00:00:00 2001 From: aanuoluwapoadegoke Date: Wed, 26 May 2021 12:27:44 +0100 Subject: [PATCH] Wed May 26 2021 12:27:44 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time) --- 12/13.txt | 2 +- 1 file changed, 1 insertion(+), 1 deletion(-) diff --git a/12/13.txt b/12/13.txt index 42b0d4c..baab3e0 100644 --- a/12/13.txt +++ b/12/13.txt @@ -1 +1 @@ -\v 13 NÍgbà náà ni wọ́n rán àwọn Farisí pẹ̀lú àwọn kan tí í ṣe ọmọ-ẹ̀yìn Herodu wá sọ́dọ̀ Jesu, láti fi ọ̀rọ̀ rẹ̀ mú. \v 14 Bí wọn ti dé, wọ́n wí pé: “Olùkọ́, àwa mọ̀ pé ìwọ máa ń sọ òtítọ́ láìsí ìbẹ̀rù ẹnikẹ́ni. Òtítọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ni ìwọ máa ń kọ́ni. Ńjẹ́ ó tọ́ tàbí kò tọ́ láti máa san owó orí fún Kesari?” Kí àwa kí ó san án, tàbí kí a máa san án? \v 15 Ṣùgbọ́n Jesu mọ ìwà àgàbàgebè wọn, Ó sì wí pé, “Èéṣe tí ẹ̀yin fi n dán mi wo? Ẹ mú owó idẹ kan wá kí n wò ó.” \ No newline at end of file +\v 13 NÍgbànáà ni wọ́n rán àwọn Farisí pẹ̀lú àwọn kan tí í ṣe ọmọ-ẹ̀yìn Herodu wá sọ́dọ̀ Jesu, láti fi ọ̀rọ̀ rẹ̀ mú. \v 14 Bí wọn ti dé, wọ́n wí pé: “Olùkọ́, àwa mọ̀ pé ìwọ máa ń sọ òtítọ́ láìsí ìbẹ̀rù ẹnikẹ́ni. Òtítọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ni ìwọ máa ń kọ́ni. Ńjẹ́ ó tọ́ tàbí kò tọ́ láti máa san owó orí fún Kesari?” Kí àwa kí ó san án, tàbí kí a máa san án? \v 15 Ṣùgbọ́n Jesu mọ ìwà àgàbàgebè wọn, Ó sì wí pé, “Èéṣe tí ẹ̀yin fi n dán mi wo? Ẹ mú owó idẹ kan wá kí n wò ó.” \ No newline at end of file