Thu May 20 2021 14:58:13 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
aanuoluwapoadegoke 2021-05-20 14:58:13 +01:00
parent bdabcd4966
commit 9739ffb03f
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 24 \v 25 dd
\v 24 Jesu wí fún wọn pé, “Kì í há ṣe nítorí èyí ni ẹ ṣe ṣìnà, nítorí ẹ̀yin kò mọ ìwé Mímọ́ tàbí agbára Ọlọ́run? \v 25 Nítorí pé, nígbà tí àwọn arákùnrin méje yìí àti obìnrin náà bá jí dìde nínú òkú, a kò ní ṣe ìgbéyàwó fún wọn. Wọn yóò dàbí àwọn angẹli tí ń bẹ ní ọ̀run.