Thu May 20 2021 14:52:13 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
aanuoluwapoadegoke 2021-05-20 14:52:13 +01:00
parent ce4e82e95f
commit 80d047f3a4
3 changed files with 4 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 18 Nígbànáà ni àwọn Sadusí, tí ó wípé kò sí àjíǹde, tún wá sọ́dọ̀ rẹ̀. Wọ́n biì léèrè pé, 19“Olùkọ́, Mose fún wa ní òfin pé: Nígbà tí ọkùnrin kan bá kú láìbí ọmọ, arákùnrin rẹ̀ gbọdọ̀ ṣú ìyàwó náà lópó kí wọn sì bímọ ní orúkọ ọkọ tí ó kú náà. \v 19 ss
\v 18 Nígbànáà ni àwọn Sadusí, tí ó wípé kò sí àjíǹde, tún wá sọ́dọ̀ rẹ̀. Wọ́n biì léèrè pé, \v 19 “Olùkọ́, Mose fún wa ní òfin pé, 'Nígbà tí ọkùnrin kan bá kú láìbí ọmọ, arákùnrin rẹ̀ gbọdọ̀ ṣú ìyàwó náà lópó kí wọn sì bímọ ní orúkọ ọkọ tí ó kú náà.

1
12/20.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 20 Àwọn arákùnrin méje kan wà, èyí tí ó dàgbà jùlọ gbéyàwó, ó sì kú ní àìlọ́mọ. 21Arákùnrin rẹ̀ kejì ṣú obìnrin tí ó fi sílẹ̀ lópó, láìpẹ́, òun pẹ̀lú tún kú láìbímọ. Arákùnrin kẹta tó ṣú obìnrin yìí lópó tún kú bákan náà láìbímọ. 22Àwọn méjèèje sì ṣú u lópó, wọn kò sì fi ọmọ sílẹ̀. Ní ìkẹyìn gbogbo wọn, obìnrin náà kú pẹ̀lú. 23Ǹjẹ́ ní àjíǹde, nígbà tí wọ́n bá jíǹde, aya ta ni yóò ha ṣe nínú wọn? Àwọn méjèèje ni ó sá ni ní aya?” \v 21 \v 22 \v 23 ss

View File

@ -97,6 +97,7 @@
"12-08",
"12-10",
"12-13",
"12-16"
"12-16",
"12-18"
]
}