diff --git a/15/06.txt b/15/06.txt index 8126dfa..f25b83f 100644 --- a/15/06.txt +++ b/15/06.txt @@ -1 +1 @@ -\v 6 Nísisìyí ni àsìkò àṣè, Pílátù máa ń fi ẹlẹ́wọ̀n kan sílẹ̀, ẹlẹ́wọ̀n tí wọ́n bá fẹ́. \v 7 Ní ibẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọlọ́tẹ̀ nínu túbú, láàrin àwọn apànìyàn tíó lọ́wọ́ nínú ọ̀tẹ̀ ni ọkùnrin tí à npe ni Baraba wà. \v 8 Èrò náà wá sí ọ̀dọ̀ Pílátù, wọ́n sì bèrè pé kó se oun tó tín se tẹ́lẹ̀ fún wọn. \ No newline at end of file +\v 6 Nísisìyí ni àsìkò àṣè, Pílátù máa ń fi ẹlẹ́wọ̀n kan lé wọn lọ́wọ́, ẹlẹ́wọ̀n tí wọ́n bá béèrè. \v 7 Ní ibẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọlọ́tẹ̀ nínu túbú, láàrin àwọn apànìyàn tíó lọ́wọ́ nínú ọ̀tẹ̀ ni ọkùnrin tí à npe ni Baraba wà. \v 8 Èrò náà wá sí ọ̀dọ̀ Pílátù, wọ́n sì bèrè pé kó se oun tó tín se tẹ́lẹ̀ fún wọn. \ No newline at end of file