Thu May 20 2021 13:44:12 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
aanuoluwapoadegoke 2021-05-20 13:44:13 +01:00
parent d24236340e
commit 7218a36d65
3 changed files with 6 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 31 Ó sì bẹ̀rẹ̀ sí kọ́ wọn pé, Ọmọ Ènìyàn kò le ṣàìmá jìyà ohun púpọ̀, a ó sì kọ̀ ọ́ sílẹ̀ láti ọwọ́ àwọn àgbàgbà, àwọn olórí àlùfáà àti àwọn olùkọ́ òfin, a ó sì pa á, lẹ́yìn ọjọ́ mẹ́ta yóò sì jíǹde. \v 32 Ó sọ èyí láìfi ohunkóhun pamọ́ fún wọn, ṣùgbọ́n Peteru pe Jesu sẹ́yìn, ó sì bẹ̀rẹ̀ si bá a wí.
\v 31 Ó sì bẹ̀rẹ̀ sí kọ́ wọn pé, Ọmọ Ènìyàn kò le ṣàìmá jìyà ohun púpọ̀, a ó sì kọ̀ ọ́ sílẹ̀ láti ọwọ́ àwọn àgbàgbà, àwọn olórí àlùfáà àti àwọn olùkọ́ òfin, a ó sì pa á, lẹ́yìn ọjọ́ mẹ́ta yóò sì jíǹde. \v 32 Ó sọ èyí láìfi ohunkóhun pamọ́ fún wọn. Peteru pe Jesu sẹ́yìn, ó sì bẹ̀rẹ̀ si bá a wí.

3
08/33.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1,3 @@
\v 33 Ṣùgbọ́n Jesu yípadà, ó wo àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀. Ó sì dá Peteru lẹ́kun, “Kúrò lẹ́yìn mi, Satani! Iwọ kò ro ohun tí Ọlọ́run bí kò ṣe ohun tí ènìyàn.”
Ọ̀nà sí àgbélébùú
34 Nígbà náà ni Jesu pe àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ àti ọ̀pọ̀ ènìyàn láti bá wọn sọ̀rọ̀, ó wí fún wọn pé, “Bí ẹnikẹ́ni bá fẹ́ tọ̀ mí lẹ́yìn, kí ó sẹ́ ara rẹ̀, kí ó si gbé àgbélébùú rẹ̀, kí ó si máa tọ̀ mi lẹ́yìn.\v 34 dd

View File

@ -85,6 +85,7 @@
"08-22",
"08-24",
"08-27",
"08-29"
"08-29",
"08-31"
]
}