From 6c83965c255d1e5f8cfa2d3aad9435521aae7fda Mon Sep 17 00:00:00 2001 From: aanuoluwapoadegoke Date: Thu, 20 May 2021 13:10:12 +0100 Subject: [PATCH] Thu May 20 2021 13:10:12 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time) --- 08/11.txt | 2 +- 1 file changed, 1 insertion(+), 1 deletion(-) diff --git a/08/11.txt b/08/11.txt index ad11cb7..1600788 100644 --- a/08/11.txt +++ b/08/11.txt @@ -1 +1 @@ -\v 11 NÍgbà náà ni àwọn Farisí jáde wá, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí ń se àríyànjiyàn pẹ̀lú u rẹ̀. Wọ́n ń wá ààmì láti ọ̀run wá lọ́wọ̀ ọ reLáti dán an wò, . 12Jesu mí kanlẹ̀, nígbà tí ó gbọ́ ìbéèrè wọn. Ó sì dáhùn wí pé, “Èéṣe tí ìran yìí fi ń wá ààmì? Lóòótọ́ ni mo sọ fún un yín kò si ààmì tí a ó fi fún ìran yín.” 13Nígbà náà ni ó padà sínú ọkọ̀ ojú omi ó fi àwọn ènìyàn sílẹ̀, ó sì rékọjá sí apá kejì Òkun náà.\v 12 \v 13 ss \ No newline at end of file +\v 11 NÍgbà náà ni àwọn Farisí jáde wá, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí ń se àríyànjiyàn pẹ̀lú u rẹ̀. Wọ́n ń wá ààmì láti ọ̀run wá lọ́wọ̀ ọ rẹ̀, láti dán an wò. 13Nígbà náà ni ó padà sínú ọkọ̀ ojú omi ó fi àwọn ènìyàn sílẹ̀, ó sì rékọjá sí apá kejì Òkun náà.\v 12 Ó mí kanlẹ̀ ní ọkàn an rẹ̀ ó wípé, “Èéṣe tí ìran yìí fi ń wá ààmì? Lóòótọ́ ni mo wí fún un yín kò si ààmì tí a ó fi fún ìran yín.”\v 13 ss \ No newline at end of file