Thu May 20 2021 13:16:12 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
aanuoluwapoadegoke 2021-05-20 13:16:13 +01:00
parent 3ce5bc5a69
commit 590f1fba4e
3 changed files with 5 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 14 Àwọn ọmọ ẹ̀yìn ti gbàgbé láti mú àkàrà lọ́wọ́. Ẹyọ ìṣù àkàrà kan ṣoṣo ni ó wà nínú ọkọ̀ wọn. \v 15 Jesu kìlọ̀ fún wọn pé, Bí wọ́n sì ti ń rékọjá, “Ẹ máa ṣọ́ra nítorí ìwúkàrà àwọn Farisi àti ìwúkàrà Herodu.”
\v 14 Àwọn ọmọ ẹ̀yìn ti gbàgbé láti mú àkàrà lọ́wọ́. Ẹyọ ìṣù àkàrà kan ṣoṣo ni ó wà nínú ọkọ̀ wọn. \v 15 Jesu kìlọ̀ fún wọn pé, “Ẹ máa ṣọ́ra nítorí ìwúkàrà àwọn Farisí àti ìwúkàrà Hẹ́rọ́dù.”

2
08/16.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1,2 @@
\v 16 Àwọn ọmọ ẹyìn sí bẹ̀rẹ̀ sí ronú èyí láàrín ara wọn wí pé, “Torí pé a kò mú àkàrà lọ́wọ́ ni?”
17 Jesu mọ ohun tí wọ́n sọ láàrín ara wọn, ó sì dá wọn lóhùn pé, “Èéṣe ti ẹ̀yin fi ń ṣe àròyé pé ẹ̀yin kò mú àkàrà lọ́wọ́? Ẹ̀yin kò kíyèsi i títí di ìsinsin yìí, ẹ kò sì ti mòye, àbí ọkàn yín le ni. \v 17 dd

View File

@ -77,6 +77,7 @@
"08-01",
"08-05",
"08-07",
"08-11"
"08-11",
"08-14"
]
}