Wed Jun 26 2019 09:55:26 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-26 09:55:27 +01:00
parent 02afa36dd5
commit 548fe9787f
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 6 Nísisìyí ni àsìkò wẹje-wẹ̀mu, Pílátù máa nfi ẹlẹ́wọ̀n sílẹ̀, ẹlẹ́wọ̀n tí wọ́n bá fẹ́. \v 7 Ní ibẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọlọ́tẹ̀ nínu túbú, láàrin àwọn apànìyàn tíó lọ́wọ́ nínú ọ̀tẹ̀ ni ọkùnrin tí à npe ni Baraba wà. \v 8 Èrò náà wá sí ọ̀dọ̀ Pílátù, wọ́n sì bèrè pé kó se oun tó tín se tẹ́lẹ̀ fún wọn.
\v 6 Nísisìyí ni àsìkò àṣè, Pílátù máa ń fi ẹlẹ́wọ̀n kan sílẹ̀, ẹlẹ́wọ̀n tí wọ́n bá fẹ́. \v 7 Ní ibẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọlọ́tẹ̀ nínu túbú, láàrin àwọn apànìyàn tíó lọ́wọ́ nínú ọ̀tẹ̀ ni ọkùnrin tí à npe ni Baraba wà. \v 8 Èrò náà wá sí ọ̀dọ̀ Pílátù, wọ́n sì bèrè pé kó se oun tó tín se tẹ́lẹ̀ fún wọn.