From 52be443d7aa6eb456aaceaa0c56185347b60d625 Mon Sep 17 00:00:00 2001 From: tsDesktop Date: Fri, 17 May 2019 12:05:22 -1200 Subject: [PATCH] Fri May 17 2019 12:05:21 GMT-1200 (Dateline Standard Time) --- 05/41.txt | 2 +- 1 file changed, 1 insertion(+), 1 deletion(-) diff --git a/05/41.txt b/05/41.txt index 46d3b01..6cd0a1a 100644 --- a/05/41.txt +++ b/05/41.txt @@ -1 +1 @@ -\v 41 Ó sì mu ọwọ́ ọmọ náà ó sì wí fún wípé, "Talitha Koum!" èyí tí ó túmọ̀ sí wípé, "ọmọbìnrin, mo wí fún ọ, dìdé." \v 42 Lójú kanáà, ọmọ náà didé, ó sì ń rìn (Ó jé ọmọ ọdún méjìlá nigbana). Lẹ́sẹ̀kánnà ẹnu yà wọ́n ìbẹ̀rù bojo sì mú ọkàn wọn. \v 43 Ó sì pàsẹ fún wọn wípé, ẹnikẹ́ni kò gbọdọ̀ mọ̀ ní pa rẹ̀. Ó sì wí fún wọn wípé, ki wọn fun louje je. \ No newline at end of file +\v 41 Ó sì mu ọwọ́ ọmọ náà ó sì wí fún wípé, "Talitha Koum!" èyí tí ó túmọ̀ sí wípé, "ọmọbìnrin, mo wí fún ọ, dìdé." \v 42 Lójú kanáà, ọmọ náà didé, ó sì ń rìn (Ó jé ọmọ ọdún méjìlá nigbana). Lẹ́sẹ̀kánnà ẹnu yà wọ́n ìbẹ̀rù bojo sì mú ọkàn wọn. \v 43 Ó sì pàsẹ fún wọn wípé, ẹnikẹ́ni kò gbọdọ̀ mọ̀ ní pa rẹ̀. Ó sì wí fún wọn wípé, kí wọn fun lóunjẹ jẹ. \ No newline at end of file