Wed Jun 26 2019 14:00:57 GMT-1200 (Dateline Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-26 14:00:58 -12:00
parent 0d392424c6
commit 48c307134e
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 21 Nígbàtí Jésù tí re kojá sí òdì kejì, nínú ọkọ̀ ojú omi, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn yii ká, bí ó ti wà lẹgbẹ òkun. \v 22 Ọ̀kan nínú àwon olùdarí sínágọ́gú, ẹní tí orúkọ rẹ̀ ńjẹ́ Jáírù, ó wáà, nígbàtí ó sì ri, o wólẹ̀ níwájú rẹ̀. \v 23 Ó bẹ̀ ẹ́, o' sì tún bẹ̀ wípé, Ọmọ mi obìnrin kékeré fẹ́rẹ̀ kú. Mo bẹ̀ Ọ́, wá dá ọwọ́ rẹ lee kí ó le padà bọ̀ sí pò kí o sì wà ní àláfíà. \v 24 Nítorína o ba lo. ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn sì ba lọ àti pé wọ́n súmọ́ pẹ́kípẹ́kí ní agbègbè náà.
\v 21 Nígbàtí Jésù tí re kojá sí òdì kejì, nínú ọkọ̀ ojú omi, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn yii ká, bí ó ti wà lẹgbẹ òkun. \v 22 Ọ̀kan nínú àwon olùdarí sínágọ́gú, ẹní tí orúkọ rẹ̀ ńjẹ́ Jáírù, ó wáà, nígbàtí ó sì ri, o wólẹ̀ níwájú rẹ̀. \v 23 Ó bẹ̀ ẹ́, ó sì tún bẹ̀ wípé, Ọmọ mi obìnrin kékeré fẹ́rẹ̀ kú. Mo bẹ̀ Ọ́, wá dá ọwọ́ rẹ lee kí ó le padà bọ̀ sí pò kí o sì wà ní àláfíà. \v 24 Nítorína o ba lo. ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn sì ba lọ àti pé wọ́n súmọ́ pẹ́kípẹ́kí ní agbègbè náà.