Wed May 26 2021 12:21:44 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
aanuoluwapoadegoke 2021-05-26 12:21:44 +01:00
parent d84c0f2c75
commit 42ef1af708
3 changed files with 3 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 33 Ṣùgbọ́n Jesu yípadà, ó wo àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀. Ó sì dá Pétérù lẹ́kun, “Kúrò lẹ́yìn mi, Sàtánì! Ìwọ kò ro ohun tí Ọlọ́run bí kò ṣe ohun tí ènìyàn.” \v 34 Nígbà náà ni Jesu pe àwọn ọ̀pọ̀ ènìyàn àti àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ jọ, ó wí fún wọn pé, “Bí ẹnikẹ́ni bá fẹ́ tọ̀ mí lẹ́yìn, ó gbọ́dọ̀ sẹ́ ara rẹ̀, kí ó gbé àgbélébùú rẹ̀, kí ó si máa tọ̀ mi lẹ́yìn.
\v 33 Ṣùgbọ́n Jesu yípadà, ó wo àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀. Ó sì dá Pétérù lẹ́kun, “Kúrò lẹ́yìn mi, Sàtánì! Ìwọ kò ro ohun tí Ọlọ́run bí kò ṣe ohun tí ènìyàn.” \v 34 Nígbànáà ni Jesu pe àwọn ọ̀pọ̀ ènìyàn àti àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ jọ, ó wí fún wọn pé, “Bí ẹnikẹ́ni bá fẹ́ tọ̀ mí lẹ́yìn, ó gbọ́dọ̀ sẹ́ ara rẹ̀, kí ó gbé àgbélébùú rẹ̀, kí ó si máa tọ̀ mi lẹ́yìn.

View File

@ -1 +1 @@
Orí kejìlá
Orí Kejìlá

View File

@ -87,6 +87,7 @@
"08-27",
"08-29",
"08-31",
"08-33",
"08-35",
"08-38",
"12-title",