Thu May 16 2019 15:33:18 GMT-0900 (Alaskan Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-16 15:33:19 -09:00
parent 3059bd4782
commit 3b52b2ccb5
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 38 Jésù dá wọn lóhùn, ẹ kò mọ ohun tí ẹ̀yin ńbèrè. Ẹ̀ yín a le mu ife tí èmi yóò mu tàbí farada ìtẹ̀bọmi tí a ó fi rì mí bọmi?" \v 39 Wọ́n wí fún pé, "àwa leè sé" Jésù wí fún wọn pé , ife tí èmi yóò mu ni ẹ̀yin náà yóò mu àti ìtẹ̀bọmi tí èmi ó se ni aó se fún ẹ̀yin náà. \v 40 Sùgbọ́n, ẹni tí yóò jókòó ní ọwọ́ ọ̀tún mi àti ní ọwọ́ òsì mi, kìí se tèmi láti fúnni bíkòse àwọn tí a ti pèsèe rẹ̀ sílẹ̀ fún."
\v 38 Jésù dá wọn lóhùn, ẹ kò mọ ohun tí ẹ̀yin ńbèrè. Ẹ̀ yín a le mu ife tí èmi yóò mu tàbí farada ìtẹ̀bọmi tí a ó fi rì mí bọmi?" \v 39 Wọ́n wí fún pé, "àwa leè sé" Jésù wí fún wọn pé , ife tí èmi yóò mu ni ẹ̀yin náà yóò mu àti ìtẹ̀bọmi tí èmi ó se ni aó se fún ẹ̀yin náà. \v 40 ùgbọ́n, ẹni tí yóò jókòó ní ọwọ́ ọ̀tún mi àti ní ọwọ́ òsì mi, kìí se tèmi láti fúnni bíkòse àwọn tí a ti pèsèe rẹ̀ sílẹ̀ fún."