diff --git a/15/19.txt b/15/19.txt index 4c9b880..15c5ea1 100644 --- a/15/19.txt +++ b/15/19.txt @@ -1 +1 @@ -\v 19 Wón lu orì rẹ̀ pẹ̀lú ọ̀pá, wọ́n sì tu itọ́ síi lára. Wọ́n kúnlẹ̀ ní wájú rẹ̀ bíì pé wón júbà rè. \v 20 Nígbàtí wọ́n ti se ẹlẹ́yà rẹ̀, wọ́n bọ́ asọ ìgúnwà elése àlùkò náà, wọ́nsì fi asọ rẹ̀ wọ̀ọ́, wón sì múu lọ láti kàán mọ́ àgbélèbú \v 21 Wọ́n fi ipá mú ẹnìkan tón kọjá lọ lẹ́bàá ọ̀nà láti gbé àgbelebu Jesu, okunrin ti a npe oruke re ni Simoni ara Kireni, baba Alesanda ati Rufusi. \ No newline at end of file +\v 19 Wón lu orì rẹ̀ pẹ̀lú ọ̀pá, wọ́n sì tu itọ́ síi lára. Wọ́n kúnlẹ̀ ní wájú rẹ̀ bíì pé wón júbà rè. \v 20 Nígbàtí wọ́n ti se ẹlẹ́yà rẹ̀, wọ́n bọ́ asọ ìgúnwà elése àlùkò náà, wọ́nsì fi asọ rẹ̀ wọ̀ọ́, wón sì múu lọ láti kàán mọ́ àgbélèbú \v 21 Wọ́n fi ipá mú ẹnìkan tón kọjá lọ lẹ́bàá ọ̀nà láti gbé àgbélèbú Jésù, ọkùnrin tí à npé orúkọ rẹ̀ ní Símónì ará Kireni, bàbá Alesanda ati Rufusi. \ No newline at end of file