diff --git a/12/20.txt b/12/20.txt index a8c2cf9..52261b8 100644 --- a/12/20.txt +++ b/12/20.txt @@ -1 +1 @@ -\v 20 Àwọn arákùnrin méje kan wà, èyí tí ó dàgbà jùlọ gbéyàwó, ó sì kú ní àìlọ́mọ. 21Arákùnrin rẹ̀ kejì ṣú obìnrin tí ó fi sílẹ̀ lópó, láìpẹ́, òun pẹ̀lú tún kú láìbímọ. Arákùnrin kẹta tó ṣú obìnrin yìí lópó tún kú bákan náà láìbímọ. 22Àwọn méjèèje sì ṣú u lópó, wọn kò sì fi ọmọ sílẹ̀. Ní ìkẹyìn gbogbo wọn, obìnrin náà kú pẹ̀lú. 23Ǹjẹ́ ní àjíǹde, nígbà tí wọ́n bá jíǹde, aya ta ni yóò ha ṣe nínú wọn? Àwọn méjèèje ni ó sá ni ní aya?” \v 21 \v 22 \v 23 ss \ No newline at end of file +\v 20 Àwọn arákùnrin méje kan wà; èyí tí ó dàgbà jùlọ gbéyàwó, ó sì kú ní àìlọ́mọ. 23Ǹjẹ́ ní àjíǹde, nígbà tí wọ́n bá jíǹde, aya ta ni yóò ha ṣe nínú wọn? Àwọn méjèèje ni ó sá ni ní aya?” \v 21 Arákùnrin rẹ̀ kejì ṣú obìnrin tí ó fi sílẹ̀ lópó, òun pẹ̀lú tún kú láìbímọ. Bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ni arákùnrin kẹta. \v 22 Àwọn méjèèje sì ṣú u lópó, wọn kò sì fi ọmọ sílẹ̀. Ní ìkẹyìn gbogbo wọn, obìnrin náà kú pẹ̀lú. \v 23 ss \ No newline at end of file