Wed May 26 2021 12:33:44 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
aanuoluwapoadegoke 2021-05-26 12:33:44 +01:00
parent a50b79509d
commit 3397e94cb4
2 changed files with 2 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 38 Nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ Jésù wípé, “Ẹ ṣọ́ra fun àwọn olùkọ́ òfin, tí wọ́n fẹ́ láti máa wọ aṣọ gígùn káàkiri, tí wọ́n sì fẹ́ ìkíni ní ọjà \v 39 àti ibùjókòó ọlá nínú Sinagọgu àti ipò ọlá níbi àsè. \v 40 Wọ́n a tún máa jẹ ilé àwọn opó rún, tí wọ́n sì ń gbàdúrà gígùn fún àsehàn. Àwọn wọ̀nyí yíò wa ìdálẹ́bi púpọ̀."
\v 38 Nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ Jésù wípé, “Ẹ ṣọ́ra fun àwọn olùkọ́ òfin, tí wọ́n fẹ́ láti máa wọ aṣọ gígùn káàkiri, tí wọ́n sì fẹ́ ìkíni ní ọjà \v 39 àti ibùjókòó ọlá nínú Sínágọ́gù àti ipò ọlá níbi àsè. \v 40 Wọ́n a tún máa jẹ ilé àwọn opó rún, tí wọ́n sì ń gbàdúrà gígùn fún àsehàn. Àwọn wọ̀nyí yíò wa ìdálẹ́bi púpọ̀."

View File

@ -105,6 +105,7 @@
"12-28",
"12-32",
"12-35",
"12-38",
"12-41",
"12-43"
]