diff --git a/08/07.txt b/08/07.txt index 0318c5b..9d97882 100644 --- a/08/07.txt +++ b/08/07.txt @@ -1 +1 @@ -\v 7 Wọ́n tún ní àwọn ẹja wẹ́wẹ́ díẹ̀ pẹ̀lú, Jesu tún dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run fún ìpèsè náà, ó sì pàṣẹ fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ láti pín wọn fún àwọn ènìyàn náà. 8Gbogbo ọ̀pọ̀ ènìyàn náà ló jẹ àjẹyó àti àjẹtẹ́rùn. Lẹ́yìn èyí wọ́n kó àjẹkù ti ó kù jọ, agbọ̀n méje sì kún. 9Àwọn tí ó jẹ ẹ́ tó ìwọ̀n ẹgbàajì (4,000) ènìyàn, ó sì rán wọn lọ. 10Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, lẹ́yìn èyí, Jesu wọ inú ọkọ̀ ojú omi pẹ̀lú àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀, wọ́n sì gúnlẹ̀ sí agbègbè Dalmanuta.\v 8 \v 9 \v 10 ss \ No newline at end of file +\v 7 Wọ́n tún ní àwọn ẹja wẹ́wẹ́ díẹ̀ pẹ̀lú, lẹ́yìn tí ó dúpẹ́, ó pàṣẹ fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ láti pín wọn fún àwọn ènìyàn náà. 9Àwọn tí ó jẹ ẹ́ tó ìwọ̀n ẹgbàajì (4,000) ènìyàn, ó sì rán wọn lọ. 10Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, lẹ́yìn èyí, Jesu wọ inú ọkọ̀ ojú omi pẹ̀lú àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀, wọ́n sì gúnlẹ̀ sí agbègbè Dalmanuta.\v 8 Wọ́n jẹun ọ̀pọ̀ ènìyàn náà ló jẹ àjẹyó àti àjẹtẹ́rùn. Lẹ́yìn èyí wọ́n kó àjẹkù ti ó kù jọ, agbọ̀n méje sì kún.\v 9 \v 10 ss \ No newline at end of file