Thu Jun 27 2019 09:39:05 GMT-1200 (Dateline Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-27 09:39:07 -12:00
parent ed4a34ae6c
commit 2e9ee7fd48
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 30 Jésù sì ní ìmọ̀lára wípé agbára ti jáde kúrò lára òhun. Ó wò yíká láàrín èrò wípé, "tani ó fọwọ́ kan asọ mi?". \v 31 Àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ wí fún pé, "O ri bi àwọn ènìyàn yìí tí yípo rẹ, ó sì ni, "tani ó fọwọ́ kàn mí?" \v 32 Jésù wò yíká láti rí ẹni tó ṣe eléyìí.
\v 30 Jésù sì ní ìmọ̀lára lẹ́ṣẹ̀kẹṣẹ̀ wípé agbára ti jáde kúrò lára òhun. Ó wò yíká láàrín èrò wípé, "tani ó fọwọ́ kan asọ mi?". \v 31 Àwọn ọmọ ẹ̀yìn Rẹ̀ wí fún pé, "O ri bi àwọn ènìyàn yìí tí yípo rẹ, ó sì ni, "tani ó fọwọ́ kàn mí?" \v 32 Jésù wò yíká láti rí ẹni tó ṣe eléyìí.