Tue May 18 2021 11:30:47 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
aanuoluwapoadegoke 2021-05-18 11:30:48 +01:00
parent fe50c29bcc
commit 133f654fa8
3 changed files with 4 additions and 4 deletions

View File

@ -1,3 +1 @@
\v 19 Bí Jésù sì ti rìn síwájú díẹ̀, Ó rí Jakọbu ọmọ Sébédè àti Jòhánù arákùnrin rẹ̀, wọ́n wa nínú ọkọ̀ wọ́n ń tún àwọ̀n wọn ṣe.
\v 20 Ó ké wọn, wọ́n sì fi Sebede baba wọn sílẹ̀ nínú ọkọ̀ pẹ̀lú àwọn alágbàṣe, wọ́n sì tọ̀ ọ́ lẹ́yìn.
Jesu lé ẹ̀mí àìmọ́ jáde
\v 19 Bí Jésù sì ti rìn síwájú díẹ̀, Ó rí Jakọbu ọmọ Sébédè àti Jòhánù arákùnrin rẹ̀, wọ́n wa nínú ọkọ̀ wọ́n ń tún àwọ̀n wọn ṣe. \v 20 Ó ké wọn, wọ́n sì fi Sébédè baba wọn sílẹ̀ nínú ọkọ̀ pẹ̀lú àwọn alágbàṣe, wọ́n sì tọ̀ ọ́ lẹ́yìn.

1
01/21.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 21 Lẹ́yìn náà wọ́n wọ Kápérnáúmu, nígbà tí ó di òwúrọ̀ ọjọ́ ìsinmi, ó lọ sínú Sinagọgu, ó sì ń kọ́ni. 22Ẹnu sì ya ìjọ ènìyàn nítorí ìkọ́ni rẹ̀, nítorí pé ó ń kọ́ni bí ẹni tí ó ní àṣẹ, kì í ṣe bí àwọn olùkọ́ òfin ṣe ń kọ́ àwọn ènìyàn. \v 22 ọọ

View File

@ -44,6 +44,7 @@
"01-09",
"01-12",
"01-14",
"01-16"
"01-16",
"01-19"
]
}