diff --git a/08/07.txt b/08/07.txt index e189baa..96c2a44 100644 --- a/08/07.txt +++ b/08/07.txt @@ -1 +1 @@ -\v 7 Wọ́n tún ní àwọn ẹja wẹ́wẹ́ díẹ̀ pẹ̀lú, lẹ́yìn tí ó dúpẹ́, ó pàṣẹ fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ láti pín wọn fún àwọn ènìyàn náà. \v 8 Wọ́n jẹun wọ́n sì yó, wọ́n kó àjẹkù ti ó kù jọ, agbọ̀n méje sì kún. \v 9 Àwọn tí ó wà níbẹ̀ tó ìwọ̀n ẹgbàajì ènìyàn. Ó sì rán wọn lọ. \v 10 Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, ó wọ inú ọkọ̀ ojú omi pẹ̀lú àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀, wọ́n sì lọ sí agbègbè Dalmanuta. \ No newline at end of file +\v 7 Wọ́n tún ní àwọn ẹja wẹ́wẹ́ díẹ̀ pẹ̀lú, lẹ́yìn tí ó dúpẹ́, ó pàṣẹ fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ láti pín wọn fún àwọn ènìyàn náà. \v 8 Wọ́n jẹun wọ́n sì yó, wọ́n kó àjẹkù ti ó kù jọ, agbọ̀n méje sì kún. \v 9 Àwọn tí ó wà níbẹ̀ tó ìwọ̀n ẹgbàajì ènìyàn. Ó sì rán wọn lọ. \v 10 Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, ó wọ inú ọkọ̀ ojú omi pẹ̀lú àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀, wọ́n sì lọ sí agbègbè Dálímánútà. \ No newline at end of file diff --git a/08/11.txt b/08/11.txt index 93becbe..0979342 100644 --- a/08/11.txt +++ b/08/11.txt @@ -1 +1 @@ -\v 11 NÍgbà náà ni àwọn Farisí jáde wá, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí ń se àríyànjiyàn pẹ̀lú u rẹ̀. Wọ́n ń wá ààmì láti ọ̀run wá lọ́wọ̀ ọ rẹ̀, láti dán an wò. \v 12 Ó mí kanlẹ̀ ní ọkàn an rẹ̀ ó wípé, “Èéṣe tí ìran yìí fi ń wá ààmì? Lóòótọ́ ni mo wí fún un yín, kò si ààmì tí a ó fi fún ìran yín.” \v 13 Nígbà náà ni fi wọ́n sílẹ̀, ó padà sínú ọkọ̀ ojú omi, ó sì rékọjá sí apá kejì Òkun náà. \ No newline at end of file +\v 11 NÍgbànáà ni àwọn Farisí jáde wá, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí ń se àríyànjiyàn pẹ̀lú u rẹ̀. Wọ́n ń wá ààmì láti ọ̀run wá lọ́wọ̀ ọ rẹ̀, láti dán an wò. \v 12 Ó mí kanlẹ̀ ní ọkàn an rẹ̀ ó wípé, “Èéṣe tí ìran yìí fi ń wá ààmì? Lóòótọ́ ni mo wí fún un yín, kò si ààmì tí a ó fi fún ìran yín.” \v 13 Nígbà náà ni fi wọ́n sílẹ̀, ó padà sínú ọkọ̀ ojú omi, ó sì rékọjá sí apá kejì Òkun náà. \ No newline at end of file