adesinaabegunde_yo_mrk_text.../15/14.txt

1 line
324 B
Plaintext
Raw Normal View History

\v 14 Pílátù sì wí fún wọn, "Kíni aìda tó se?" Sùgbọ́n wọ́n tún pariwo sókè, "Kàán mọ́ àgbélèbú." \v 15 Pílátù fẹ́ tẹ́ àwọn èrò náà lọ́rùn, nítorínà, ó fi Bárábà sílẹ̀ fún wọn. Ósì naa Jésù, ósì fi lé wọn lọ́wọ́ láti kàán mọ́ àgbélèbú.