adesinaabegunde_yo_mrk_text.../15/09.txt

1 line
357 B
Plaintext
Raw Normal View History

\v 9 Pílátù dawọn lóhùn wípé, "Ǹjẹ́ ẹ̀yin fẹ́ kí èmi fi Ọba àwọn Júù lé e yín lọ́wọ́ ni?" \v 10 Nítorí ó mọ̀ pé àwọn olórí àlùfáà fi Jésù lé òun lọ́wọ́ nítorí owú ni \v 11 Sùgbọ́n àwọn olórí àlùfa ru àwọn èrò sókè láti pariwo pé Baraba ni kí ó fi sílẹ̀ ẹ̀wẹ̀.