adesinaabegunde_yo_mat_text.../28/14.txt

1 line
353 B
Plaintext

\v 14 Tí ìròyìn yìí bá dé ọ̀dọ̀ gómìnà, ẹ máṣe mikàn nítorí a ó bá a sọ̀rọ̀ láti má fìyà jẹyín." \v 15 Nígbà náà ni àwọn ọmọ ogun náà gba owó náà wọ́n sì ṣe gẹ́gẹ́ bí a ti sọ fún wọn. Ìròyìn yìí tàn kálẹ̀ láàrin àwọn Júù ó ṣi tẹ̀ síwájú títí di òní.