adesinaabegunde_yo_mat_text.../21/31.txt

1 line
546 B
Plaintext

\v 31 Èwo nínú àwọn ọmọ méjéjì ló ṣe ìfẹ́ baba?'' wọ́n wípé, ''ọmọ àkọ́kọ́.'' Jésù ṣọ fún wọn pé, ''lótìtọ́ ni mo wí fún yín, àwọn agbowóòde àti àwọn alágbérè yóò wọ ìjọba Ọlọ́run sájú yín. \v 32 Nítorítí Jòhánù wá ní ọ̀nà òdodo, ṣùgbọ́n ẹ̀yin kò gbàágbọ́. Ṣùgbọ́n àwọn agbowó òde àti àwọn alágbérè gbàágbọ́. Ṣùgbọ́n ẹ̀yin, nígbàtí ẹ ríi èyí, ẹ kò ronúpíwàdà, ẹ kò tún gbàágbọ́.