adesinaabegunde_yo_mat_text.../10/37.txt

1 line
422 B
Plaintext

\v 37 Ẹnití ó bá fẹ́ràn baba tabi ìyá rẹ̀ jù mí lọ, kò yẹ ní tèmi; ẹni tí ó bá sì fẹ́ràn ọmọ rẹ̀ ọkunrin tabi obinrin jù mí lọ, kò yẹ ní tèmi. \v 38 Ẹni tí kò bá gbé agbelebu rẹ̀, kí ó máa tẹ̀lé mi, kò yẹ ní tèmi. \v 39 Ẹni tí ó bá gba ẹ̀mí rẹ̀ là yóo pàdánù rẹ̀. Sùgbọn ẹni tí ó bá pàdánù ẹ̀mí rẹ̀ nítorí mi yóò rí i.