adesinaabegunde_yo_mat_text.../10/32.txt

1 line
294 B
Plaintext

\v 32 Nítorí náà, ẹnikẹ́ni tí ó bá jẹ́wọ́ mi níwájú eniyan, Èmi náà yóo jẹ́wọ́ rẹ̀ níwájú Bàbá à mi tí ń bẹ lọ́run. \v 33 Ṣugbọn ẹnikẹ́ni tí ó bá sẹ́ mi níwájú eniyan, Èmi náà yóo sẹ́ ẹ níwájú Bàbá à mi tí ń bẹ lọ́run.