adesinaabegunde_yo_mat_text.../10/19.txt

1 line
321 B
Plaintext

\v 19 Nígbàtí wọ́n bá sì jọ̀wọ́ yín, ẹ máse se àníyàn nípa báwo tàbí ohun tí ẹ̀yin ó sọ, nítorí a ó fun yín ní ohun tí ẹ̀yin ó wí ní àkókò náà. \v 20 Nítorí ẹ̀yin kọ́ lẹ ó ò sọ̀rọ̀; ṣùgbọ́n Ẹ̀mi Bàbá yín ni ó sọ̀rọ̀ jáde nínú yín.