adesinaabegunde_yo_mat_text.../10/11.txt

1 line
386 B
Plaintext

\v 11 Ìlú kílǔ tàbí abúlé tí ẹ bá wọ̀, ẹ se ìwádǐ ẹnití ó yẹ níbẹ̀, kí ẹ sì dé sí ọ̀dọ rẹ̀ títí ẹ ó fi kúrò níbẹ̀. \v 12 Bí e bá wọlé, ẹ kí wọn \v 13 Bí ilé náà bá yẹ, kí àlááfìà yín kí ó wá sórí rẹ̀, ṣùgbọ́n tí ilé náà kò bá yẹ, kí àlááfìà yín kí ó padà sọ́dọ̀ yín.