adesinaabegunde_yo_mat_text.../10/05.txt

1 line
403 B
Plaintext

\v 5 Àwọn méjìlá yǐ ni Jésù rán jáde. Ó sì wí fún wọn pé, "Ẹ má se lọ sí ibi tí àwọn kèfèrí ba ń gbé, ẹ má sì se lọ sí ìlú tí ó jẹ́ ti àwọn ará a Samáríà. \v 6 Dípò bẹ́ẹ̀, ẹ lọ sí ọ̀dọ̀ àwọn àgùntàn ilé Israeli tí ó sọnù; \v 7 bí ẹ sì ti ń lọ, ẹ wàásù kí ẹ sì wípe, 'Ìjọba ọ̀run sún mọ́.'