adesinaabegunde_yo_mat_text.../10/02.txt

1 line
488 B
Plaintext

\v 2 Orúkọ àwọn ọmọ ẹ̀yìn méjìlá náà nì wọ̀n yí. Àkọ́kọ́, Símónì (ẹnití Ó tún pè ní Pétérù), àti Áńdérù tí ó jẹ́ arákùnrin rẹ̀; Jémísì ọmọ Sébédè, àti Jòhánù tí ó jẹ́ arákùnrin rẹ̀; \v 3 Fílípì, àti Batilómẹ́ù; Tómásì, àti Máttíù agbowó orí; Jémísì ọmọ Álfáúsì, àti Tádẹ́úsì; \v 4 Símónì ajíjágbára, àti Júdásì Ìsìkáríotù, ẹni tí ó sẹ́ Jésù.