adesinaabegunde_yo_mat_text.../09/12.txt

1 line
367 B
Plaintext

\v 12 Nígbàtí Jésù gbọ́ èyí, Ó wípé, "Ènìyàn tí ara rẹ̀ yá kò nílò olùwòsàn, bíkòṣe àwọn tí ara wọn kò dàá \v 13 Ó yẹ kí ẹ lọ kọ́ ìtumọ̀ èyí, 'Èmi ńfẹ́ àánú, kì í sì ǹṣe ẹbọ'. Nítorí tí èmi kò wá fún àwon olódòdo láti yípadà ṣùgbọ́n nítorí ti àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀.