adesinaabegunde_yo_mat_text.../02/11.txt

1 line
470 B
Plaintext

\v 11 Wọ́n wọ inú ilé, wọ́n sì rí ọmọ ọwọ náà pẹ̀lú Màríà ìyá rẹ̀. Wọ́n wólẹ̀, wón sì fi orí balẹ̀, wọ́n sì jọ́sìn fún un. Wọ́n tú àpò ìsura wọ́n láti fún un ní ẹ̀bùn wúrà, tùràrí, àti òjìá. \v 12 Ọlọ́run kìlọ́ fún wọn ní ojú àlá láti máse padà sí ọ̀dọ̀ Hẹ́rọ́dù, nítorínáà, wọ́n padà sí orílẹ́-èdè tiwon nípa ọ̀nà ibòmíràn.