|
\c 28 \v 1 Ó sì ṣe ní alẹ́ ọjọ́ ìsinmi, ní àfẹ̀júmọ́ ọjọ́kínní ọ̀ṣẹ̀, Màríà ará Mágdálà àti Màríà kejì wá láti wo ibojì náà \v 2 Sìkíyèsi, ilẹ̀ ṣì mì gidigid, nítorí áńgẹ́lì Olúwa sọ̀kalẹ̀ láti ọ̀run, ó wá ó ṣì yí òkúta náà kúrò, ó ṣì jókòó lé e lórí |