adesinaabegunde_yo_mat_text.../27/17.txt

1 line
534 B
Plaintext

\v 17 Nígbàtí wón sìtún pàdépọ̀,pílátù wí fún won,"tani ẹ̀yin fẹ́ kí èmi ó dá sílẹ̀ fún yín ?Bárábà ni àbí Jésù tí óhúnjẹ́ Kírísítì?" \v 18 Ó mòn pé wón fi Jésù lé òhun lọ́wọ́ nítóripé wón kórìra rẹ̀ ni. \v 19 Nígbàtí Ó jòkó lórí àga ìdájọ́,ìyàwó rẹ̀ ránsẹ́ si ó sọ fún pé "kó má sese ohunkóhun sí aláìsẹ̀ ọkùnrin yí.nítorí òhúnti dàmú púpọ̀ lójú orun lóní fún irú àlá tí òhúnti lá níparẹ̀."