adesinaabegunde_yo_mat_text.../26/20.txt

1 line
396 B
Plaintext

\v 20 Ní àsáálẹ́, Ó jókòó làti jùmọ̀ jẹun pọ̀ pẹ̀lú àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ \v 21 Bí wọn se ń jẹun lọ, Ó wípé, "Ní òtítọ́ ni mo sọ fún yín pé, ẹnìkan nínú yín yóò dà mí." \v 22 Inú gbogbo wọn sì bàjẹ́ gidigidi gan, wọ́n sì bèèrè lọ́wọ́ Rẹ̀ lọ́kọ́ọ̀kan pé, "Olúwa, ódájú pé kìí se èmi?"