adesinaabegunde_yo_mat_text.../20/29.txt

1 line
543 B
Plaintext

\v 29 Bí wọ́n ti ń jáde kúrò láti Jẹ́ríkò, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn tẹ̀ lé e. \v 30 Àwọn afọ́jú méjì kan ṣì wà tí wọ́n jókòó lẹ́gbẹ̀ẹ́ ojú ọ̀nà. Nígbà tí wọ́n gbọ́ wípé Jésù ń kọjá lọ́, wọ́n kígbe "Olúwa, Ọmọ Dáfídì, sàánú fún wa." \v 31 Àwọn ọ̀pọ̀ ènìyàn náà bá wọn wí, wọ́n sọ fún wọ́n ẹ dákẹ́ jẹ́, ṣùgbọ́n wọ́n tún kígbe sókè jù bẹ́ẹ̀lọ "Olúwa, Ọmọ Dáfídí, ṣàánú fún wa."