adesinaabegunde_yo_mat_text.../16/05.txt

1 line
548 B
Plaintext

\v 5 Nígbàtí àwọn ọmọ ẹ̀yìn dé òdì kejì, wọ́n ti gbàgbé láti mú àkàrà lọ́wọ́. \v 6 Jésu wí fún wọn, "Ẹ kíyèsára kí ẹ sì máa sọ́ra fún ìwúkàrà àwọn Farisí àti Sadusí." \v 7 Àwọn ọmọ ẹ̀yìn sí bá ara wọn sọ̀rọ̀ wọ́n sì wípé, "Nítorípé a kò mú àkàrà lọ́wọ́ ni." \v 8 Jésù si mọ èyí ó sì wípé, "èyin onígbàgbọ́ kékeré, kí lódé tí ẹ̀yin fi ń bá ara yín sọ̀rọ̀ wípé nítorí àwa kò mú ákàrà lọ́wọ́ ni?