1 line
644 B
Plaintext
1 line
644 B
Plaintext
\v 32 Jésù si pe àwọn ọmọẹyìn rẹ̀ sí ọdọ̀ rẹ̀ ó wípé, "Àánú ọ̀pọ̀ enìyàn yí se mí, nitorí wọ́n ti dúró tì mí fún ọjọ́ mẹ́ta wọn kò sì ní ohun láti je. Èmi kò fé rán wọn lọ láì jẹun, kí àárẹ̀ má baà mú wọn ní ọnà." \v 33 Àwọn ọmọ ẹyìn siwí fún n pé, "Níbo li a ó ti rí akàrà tí yíò tó ní aginjù yí tí yíò bọ́ ọpọ̀ erò yí?" \v 34 Jésù wí fún wọn pé, "Ìsù akàrà mélǒ nió wà? Wọ́n wípé, "Méje, àti eja wẹ́wẹ́ díè." \v 35 Jésù si pàsẹ kí ọ̀pọ̀ enìyàn náà jókǒ sílẹ̀. |