adesinaabegunde_yo_mat_text.../14/28.txt

1 line
414 B
Plaintext

\v 28 \v 30 Pétérù sì dáa lóhùn, ó ṣọ pé "Olúwa, bí o bájẹ́ ìwọ ni, pàṣẹ kí èmi náà wá bá ọ lórí omi." \v 29 Jésù sì ṣọ wípé, wá. Pétérù sì jáde kúrò nínú ọkọ̀, ó sìn rìn lórí omi láti lọ bá Jésù. Sùgbọ́n nígbàtí Pétérù sì wo afẹ́fẹ́, ẹ̀rù bà á. Ó sì bẹ̀rẹ̀ sí ní rì, Ó sì kígbe pé, " Olúwa gbà mí!"