adesinaabegunde_yo_mat_text.../14/03.txt

1 line
377 B
Plaintext

\v 3 Nítorítí Hẹ́rọ́dù ti mú Jòhánù, ó dè é, ó sì jú sí nú ẹ̀wọ̀n nítorí Hẹrọdíà, ìyàwó Phílípì arákùnrin rẹ̀. \v 4 Nítorítí Jòhánù wí fun pé, "Kò tọ̀nà fún ọ láti nì i gẹ́gẹ̀bí aya rẹ." \v 5 Hẹ́rọ́dù kò bá ti pá, sùgbọ́n o bẹ̀rù àwọn ènìyàn nítorípé wọ́n kà á sí wolǐ.